Ohun Gbogbo Tàn, Ó Lẹ́wà / All Things Bright And Beautiful

Translated to Yoruba by Ayobami Temitope Kehinde (15/08/2019)

1.
Ohun gbogbo tàn,  o lẹwa
Ẹda nla, kekere
Ohun gbogbo gbọ́n, ó n yanu
Ọlọ́run dá gbogbo wọn. 

2.
'Tanna kekere to ṣi
Ẹyẹ bintin to n kọrin
O da awọ didan wọn,
Iyẹ wọn tintinni.

Ohun gbogbo tan... 

3.
Ọlọ́rọ̀ 'nu gọ̀bì rẹ,
Talaka lẹnu ọna rẹ,
O da wọn nipo depo,
O paṣẹ ipo wọn.

Ohun gbogbo tan... 

4.
Oke ese aluko,
Odo tí n ṣàn lọ,
Ìrọ̀lẹ́ àt' òwúrọ̀,
T'o n mofurufu tan.

Ohun gbogbo tan... 
  
5.
Iji tutu n'nu ọyẹ,
Orun igba ẹrun,
Èso pipọn ni ọgbà,-
Ó dá wọn lọkọ̀ọ̀kan.

Ohun gbogbo tan... 

6.
Igi giga ninu 'gbo
Ọdan ta ti n ṣere
Ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ẹ̀bá omi,
Tá n pé jọ lójúmọ́.

Ohun gbogbo tan... 

7.
O fojú fun wa lati ri
Àt' ètè̀ ká lè sọ
B'Edumare ti tobi to,
To mohun gbogbo dara.

Ohun gbogbo tan... 

(Amin)
1.
All things bright and beautiful,
All creatures great and small,
All things wise and wonderful,
The Lord God made them all.

2.
Each little flower that opens,
Each little bird that sings,
He made their glowing colours,
He made their tiny wings.

All things bright ...

3.
The rich man in his castle,
The poor man at his gate,
God made them high and lowly,
And ordered their estate.

All things bright ...

4.
The purple headed mountain,
The river running by,
The sunset and the morning,
That brightens up the sky;−

All things bright ...

5.
The cold wind in the winter,
The pleasant summer sun,
The ripe fruits in the garden,−
He made them every one:

All things bright ...

6.
The tall trees in the greenwood,
The meadows where we play,
The rushes by the water,
We gather every day;−

All things bright ...

7.
He gave us eyes to see them,
And lips that we might tell,
How great is God Almighty,
Who has made all things well.

All things bright ...

(Amen)


Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na