Iwo Lo Ye / Thou Art Worthy
Author: Pauline Mills
Translated to Yoruba by Ayobami Temitope Kehinde
Ìwọ ló yẹ, Ìwọ ló yẹ,
'Wọ ló yẹ, Olúwa Láti gba ògo, ògo àt' ọlá Ògo, ọlá, agbára. 'Torí Ìwọ ló dá ohun gbogbo 'Wọ ló dá ohun gbogbo Àti fún 'fẹ̀ Rẹ ni O ṣe dá wọn 'Wọ ló yẹ, Olúwa. |
Thou art worthy, Thou art worthy,
Thou art worthy, O Lord. To receive glory, glory and honour Glory and honor and power. For Thou hast created, hast all things created, For Thou hast created all things. And for Thy pleasure they are created; Thou art worthy, O Lord. |
Comments
Post a Comment