Ojo Oni Lo Tan

Author: S. Baring Gould
Ojo oni lo tan,
Oru sunmole:
Okunkun ti de na,
Ile si ti su.

Okunkun bo ile,
Awon 'rawo yo;
Eranko at' eiye,
Lo si 'busun won.

Jesu f' orun didun,
F' eni alare;
Je ki ibukun Re,
Pa oju mi de.

Je k' omo kerekere,
La ara rere;
S' oloko t' ewu nwu
Ni oju omi.

Ma to ju alaisan,
Ti ko r' orun sun;
Da olosa lekun
L'ona ibi won.

Ninu gbogbo oru,
Je k' angeli Re,
Ma se oluso mi,
Lori eni mi.

Source: YBH #62

Gbat' ile ba si mo,
Je k' emi dide,
B' omo ti ko l' ese,
Ni iwaju Re.

Ogo ni fun Baba,
Ati fun Omo,
Ati f' Emi Mimo,
Lai ati lailai.




Now the day is over,
Night is drawing nigh,
Shadows of the evening
Steal across the sky.



Now the darkness gathers,
Stars begin to peep,
Birds, and beasts and flowers
Soon will be asleep.

Jesus, give the weary
Calm and sweet repose;
With Thy tend'rest blessing
May our eyelids close.

Grant to little children
Visions bright of Thee;
Guard the sailors tossing
On the deep blue sea.

Comfort ev'ry suff'rer
Watching late in pain;
Those who plan some evil
From their sin restrain.



Through the long night watches
May Thine angels spread
Their white wings above me,
Watching round my bed.

When the morning wakens,
Then may I arise
Pure, and fresh, and sinless
In Thy holy eyes.

Glory to the Father,
Glory to the Son,
And to Thee, blest Spirit,
While all ages run.

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na