Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú! / How Marvellous! How Wonderful!

Author: Charles Hutchinson Gabriel
Yoruba Translator: Ayobami Temitope Kehinde


Ní ìyanu ni mo dúró
Níwájú Jésù Nasaret'
Mo sì ń wòye b' Ó ti fẹ́ mi tó
Ẹlẹ́ṣẹ̀ ta dá lẹbi

Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú!
Ni orin mi yó ma jẹ̀
Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú!
Ìfẹ́ Olùgbàlà mi. 

Fún mi, nín' ọgbà ló gbàdúrà
"Jẹ́ kí ìfẹ́ Rẹ kó ṣẹ."
Ko sun tori irora Rẹ
Ṣùgbọ́n O sunro ẹjẹ fun mi. 

Tẹduntẹdun l'angẹli woo,
Wọn wa la'taye 'mọlẹ
Lati gbé E ró 'nu ' banuje
To ru fokan mi lalẹ yẹn

Ó mẹ́ṣẹ̀ àti 'bànújẹ́ mi,
Ò fi wọ́n ṣe Tirẹ̀
Ó gbẹ́rù wúwo dé Kalfari
Ó da jìyà, Ó dá kú.

'Gbà pẹ̀lú àwọn táa rà padà 
Mo rójú Rẹ̀ níkẹhìn 
N ò fayọ̀ kọrin títí ayé
Orin ìfẹ́ Rẹ̀ fún mi. 
I stand amazed in the presence
Of Jesus the Nazarene,
And wonder how He could love me,
A sinner condemned, unclean

Refrain
How marvellous! How wonderful!
And my song shall ever be:
How marvelous! How wonderful!
Is my Savior’s love for me!


For me it was in the garden,
He prayed: “Not my will, but Thine.”
He had no tears for His own griefs,
But sweat-drops of blood for mine.

In pity angels beheld Him,
And came from the world of light
To strengthen Him in the sorrows
He bore for my soul that night.

He took my sins and my sorrows,
He made them His very own;
He bore the burden to Calv’ry,
And suffered, and died alone.

When with the ransomed in glory
His face I at last shall see,
’Twill be my joy through the ages
To sing of His love for me.







Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

Olori Ijo T'orun

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!