O Fa Mi Yo Ninu Erofo/He Brought Me Out Of The Miry Clay

Yoruba Translator: Ayobami Temitope Kehinde

Okan mi gbọgbẹ labẹ 'binu  Jehofa,
Ninu ọgbun ti ẹṣẹ mi ti mi si;
Mo ke p' Oluwa lati 'nu ẹrọfọ,
T'O fi 'yọnu fa mi yọ sọjọ wura

Egbe:
O fa mi yọ ninu ẹrọfọ 
O gbẹsẹ mi sori apata

O f'orin sin' ọkan mi loni
Orin iyin, alleluia 

O gbe mi lori Apata ẹgbẹ Rẹ,
Iṣise mi mulẹ, n o duro nibi;
Ko sewu iṣubu 'gba mo wa nihin,
Ṣugbọn n o duro titi n o fi gbade.

O fun mi l'orin, orin   iyin tuntun;
L'owurọ, l'alẹ n o maa kọọ titi ni;
Ọkan mi fo fayọ, mo dominira;
N o yin Olurapada mi t'O gba mi.

N o kọrin aanu iyanu Rẹ si mi,
N o yin tit' aye yoo fi mo p'O dara;
N o kọrin 'gbala nile lẹyin odi,
K'ọpọ le gbotitọ Rẹ k'ọn si gbaa gbọ.

N o royin ọgbun ati okunkun rẹ,
N o yin Baba mi to gbọ adura mi;
N o kọrin titun, orin ayọ t'ifẹ,
N o si gberin pẹl' awọn mimọ loke.

Translated by Ayobami Temitope Kehinde
November 3, 2023.




My heart was distressed ’neath Jehovah’s dread frown,
And low in the pit where my sins dragged me down;
I cried to the Lord from the deep miry clay,
Who tenderly brought me out to golden day.

Refrain:
He brought me out of the miry clay,
He set my feet on the Rock to stay;
He puts a song in my soul today,
A song of praise, hallelujah!

He placed me upon the strong Rock by His side,
My steps were established and here I’ll abide;
No danger of falling while here I remain,
But stand by His grace until the crown I gain.

He gave me a song, ’twas a new song of praise;
By day and by night its sweet notes I will raise;
My heart’s overflowing, I’m happy and free;
I’ll praise my Redeemer, Who has rescued me.

I’ll sing of His wonderful mercy to me,
I’ll praise Him till all men His goodness shall see;
I’ll sing of salvation at home and abroad,
Till many shall hear the truth and trust in God.

I’ll tell of the pit, with its gloom and despair,
I’ll praise the dear Father, who answered my prayer;
I’ll sing my new song, the glad story of love,
Then join in the chorus with the saints above.

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na