Ilu Wura /Golden City
Laipe idamu yin yoo pin Owo anu yoo gbe yin ga E o ri iran kedere Ilekun si ile miran Egbe A o pade ni ilu wura Ni Jerusalem' tuntun Gbogbo 'rora, omije wa ko ni si mọ́ A o dúró pẹ̀lú ogun ọrún A o ke mímọ̀ l'Oluwa A o sin, a o juba Rẹ títí ayé. Baba yoo ki wa ku abo Igbasoke lo sile Iduro wa ti de opin A wole ni ite Re Ka ma rii, agbara okunkun Tabi iku tabi iye Ko si oun to le ya Kuro n'nu 'fe Oluwa
Afara Mimo, mimo l'Odo Aguntan (Mimo, mimo l'Odo Aguntan) (Mimo ni O) Mimo, mimo l'Odo Aguntan
Translated by Ayobami Temitope Kehinde on 23/05/2021
|
Source here
|
Please I need a Yoruba version of channel of blessing
ReplyDeleteYou mean the song, "Make Me a Channel of Blessing Today"?
Delete