Ọkàn Mi Mọ̀ ’Yẹn Dájú / And That My Soul Knows Very Well
Authors: Darlene Zschech / Russell Fragar
O tàn ’mọ́lẹ̀ ojú Rẹ sára mi
Ọkàn mi mọ̀ ’yẹn dájú O gbé mi ga, mo mọ́, mo bọ́ Ọkàn mi mọ̀ ’yẹn dájú Egbe ’Gbòkè ṣídìí n ó dúró Nípa ’gbára ọwọ́ Rẹ̀ Àti n'n' ààjìn ọ̀kan Rẹ̀, n ó wà Ọkàn mi mọ̀ ’yẹn dájú. Ayọ̀, okun, mo ń rí l’ójúmọ́ Ọkàn mi mọ̀ ’yẹn dájú ’Dáríjì, ’rètí jẹ́ tèmi Ọkàn mi mọ̀ ’yẹn dájú. Translated to Yoruba by Ayobami Temitope Kehinde (28/04/2020) |
You make Your face to shine on me
Now my soul knows very well You lift me up an' I'm cleansed and free Now my soul knows very well Refrain When mountains fall, I'll stand By the power of Your hand And in Your heart of hearts, I'll dwell That my soul knows very well Joy and strength each day I find That my soul knows very well Forgiveness, hope, I know is mine That my soul knows very well Songwriters: Darlene Joyce Zschech / Russell Fragar And That My Soul Knows Very Well lyrics © Capitol Christian Music Group, Music Services, Inc Source: LyricFind |
Comments
Post a Comment