Yíyẹ L'Ọdaguntan / Worthy Is The Lamb
Author: Darlene Zschech
Translated by Ayobami Temitope Kehinde on April 12, 2020
Translated by Ayobami Temitope Kehinde on April 12, 2020
O ṣeun f'ágbèlébù Olúwa
O ṣeun fún ’díyelé t'O san
O gbẹ́ṣẹ̀, ’tìjú mi rù
Nifẹ̀ l'O wa
Pẹl' or'ọfẹ ìyanu
O ṣeun fun ’fẹ́ yii, Olúwa
O ṣeun f' ọwọ́ ta gun niṣo
O wẹ mi n'nú iṣan Rẹ,
Wàyíí mo mọ̀
’Dariji, ’tẹwogba Rẹ.
Egbe:
Yíyẹ l'Ọdaguntan
T'O joko lor' itẹ́
A de Ọ lade ọpọlọpọ
O ń jọba n'iṣẹgun
Gbigbega ni Ọ
Jésù, Ọm' Ọlọrun
Ààyò ọ̀run ti a kan mọ́gi
Yíyẹ l'Ọdaguntan
Yíyẹ l'Ọdaguntan
|
Thank you for the cross, Lord
Thank you for the price You paid Bearing all my sin and shame In love You came And gave amazing grace Thank you for this love, Lord Thank you for the nail pierced hands Washed me in Your cleansing flow Now all I know Your forgiveness and embrace Refrain: Worthy is the Lamb Seated on the throne Crown You now with many crowns You reign victorious High and lifted up Jesus Son of God The Darling of Heaven crucified Worthy is the Lamb Worthy is the Lamb ©2000 Darlene Zschech/Hillsong Publishing (ASCAP) (admin. in the US & Canada by Integrity's Hosanna! Music (ASCAP)(c/o Integrity Media, Inc. 1000 Cody Road, Mobile, AL 36695.) |
Comments
Post a Comment