Olurapada Kan Wa / There Is A Redeemer
Olurapada Kan wa Jésù, Ọm' Ọlọ́run Ọ̀dọ́-Àgùntàn, Messiah Ẹni Mímọ́ Jésù Olùràpadà mi Orúkọ tó j' orúkọ lọ Ọ̀dọ́-Àgùntàn, Messiah Tí a pa f' ẹlẹ́ṣẹ̀ O ṣeun, Baba mi, T'O f' Ọmọ Rẹ fún wa O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí Gba m' bá dúró logo N o rí ojú Rẹ Níbẹ̀, n o sin Ọba mi títí Ni ibi mímọ́ yẹn. O ṣeun, Baba mi, T'O f' Ọmọ Rẹ fún wa O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí Olurapada Kan wa Jésù, Ọm' Ọlọ́run Ọ̀dọ́-Àgùntàn, Messiah Ẹni Mímọ́ O ṣeun, Baba mi, T'O f' Ọmọ Rẹ fún wa O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí Translated to Yoruba by Ayobami Temitope Kehinde (28/05/2020) There is a redeemer Jesus, God's own Son Precious Lamb of God, Messiah Holy One Jesus my redeemer Name above all names Precious Lamb of God, Messiah Oh, for sinners slain Thank you, oh my fathe...