Olurapada Kan Wa / There Is A Redeemer

Olurapada Kan wa
Jésù, Ọm' Ọlọ́run 
Ọ̀dọ́-Àgùntàn, Messiah
Ẹni Mímọ́ 

Jésù Olùràpadà mi
Orúkọ tó j' orúkọ lọ 
Ọ̀dọ́-Àgùntàn, Messiah
Tí a pa f' ẹlẹ́ṣẹ̀ 

O ṣeun, Baba mi, 
T'O f' Ọmọ Rẹ fún wa
O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi 
Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí 

Gba m' bá dúró logo 
N o rí ojú Rẹ 
Níbẹ̀, n o sin Ọba mi títí 
Ni ibi mímọ́ yẹn. 

O ṣeun, Baba mi, 
T'O f' Ọmọ Rẹ fún wa
O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi 
Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí 

Olurapada Kan wa
Jésù, Ọm' Ọlọ́run 
Ọ̀dọ́-Àgùntàn, Messiah
Ẹni Mímọ́ 

O ṣeun, Baba mi, 
T'O f' Ọmọ Rẹ fún wa
O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi 
Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí 

O fún wa l’ Ẹ̀mí Rẹ titi 
Iṣẹ́ Rẹ laye yóò parí 


Translated to Yoruba by Ayobami Temitope Kehinde (28/05/2020)








There is a redeemer
Jesus, God's own Son
Precious Lamb of God, Messiah
Holy One

Jesus my redeemer
Name above all names
Precious Lamb of God, Messiah
Oh, for sinners slain

Thank you, oh my father
For giving us Your Son
And leaving Your Spirit
'Til the work on Earth is done

When I stand in Glory
I will see His face
And there I'll serve my King forever
In that Holy Place

Thank you, oh my father
For giving us Your Son
And leaving Your Spirit
'Til the work on Earth is done

There is a redeemer
Jesus, God's own Son
Precious Lamb of God, Messiah
Holy One

Thank you, oh my father
For giving us Your Son
And leaving Your Spirit
'Til the work on Earth is done
And leaving Your Spirit
'Til the work on Earth is done

Songwriters: Melody Green
There Is a Redeemer lyrics © Universal Music Publishing Group, Capitol Christian Music Group



Source: LyricFind


Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na