Gbayé Mi, Darí Mi o / Take My Life, Lead Me Lord
Author: R. Maines Rawls
Gbayé mi, darí mi o, Gbayé mi, darí mi o, Jẹ́ kí n lè wúlò fún Ọ. Gbayé mi, darí mi o, Gbayé mi, darí mi o, Jẹ́ kí n lè wúlò fún Ọ. Gbayé mi, kọ́ mi o, Gbayé mi, kọ́ mi o, Jẹ́ kí n lè wúlò fún Ọ. Gbayé mi, kọ́ mi o, Gbayé mi, kọ́ mi o, Jẹ́ kí n lè wúlò fún Ọ. Èmi rèé, rán mi o, Èmi rèé, rán mi o, Jẹ́ kí n lè wúlò fún Ọ. Èmi rèé, rán mi o, Èmi rèé, rán mi o, Jẹ́ kí n lè wúlò fún Ọ. |
Take my life, lead me Lord, Take my life, lead me Lord, Make my life useful to Thee. Take my life, lead me Lord, Take my life, lead me Lord, Make my life useful to Thee. Take my life, teach me Lord, Take my life, teach me Lord, Make my life useful to Thee. Take my life, teach me Lord, Take my life, teach me Lord, Make my life useful to Thee. Here am I, send me Lord, Here am I, send me Lord, Make my life useful to Thee. Here am I, send me Lord, Here am I, send me Lord, Make my life useful to Thee. Source: Baptist Hymnal 1991
|
Comments
Post a Comment