Káàkiri Ayé / All Over The World world

Káàkiri ayé Ẹ̀mí ń rábabà,  
Káàkiri ayé báwọn wòlíì ti sọ tẹ́lẹ̀; 
Káàkiri ayé ìṣípayá ńlá kan wà 
Ti ògo Olúwa, bi omi ti bo òkun. 

Yíká ìjọ Rẹ̀ Ẹ̀mí ń rábabà,  
Yíká ìjọ Rẹ̀ báwọn wòlíì ti sọ tẹ́lẹ̀; 
Yíká ìjọ Rẹ̀ ìṣípayá ńlá kan wà 
Ti ògo Olúwa, bi omi ti bo òkun. 

Ní ìhín yìí Ẹ̀mí ń rábabà,  
Ní ìhín yìí báwọn wòlíì ti sọ tẹ́lẹ̀; 
Ní ìhín yìí ìṣípayá ńlá kan wà 
Ti ògo Olúwa, bi omi ti bo òkun. 

Translated to Yoruba by Ayobami Temitope Kehinde (02/06/2020)








All over the world the Spirit is moving,
All over the world as the prophet said it would be;
All over the world there's a mighty revelation
Of the glory of the Lord, as the waters cover the sea.

All over His church God's Spirit is moving,
All over His church as the prophet said it would be;
All over His church there's a mighty revelation
Of the glory of the Lord, as the waters cover the sea.

Right here in this place the Spirit is moving,
Right here in this place as the prophet said it would be;
Right here in this place there's a mighty revelation
Of the glory of the Lord, as the waters cover the sea.

Author: Roy Turner
© 1984 Thankyou Music

Source: weareworship




Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na