FUN ẸWA ILE AYE /FOR THE BEAUTY OF THE EARTH

Credit: Pexels.com

Author: Folliott Sandford Pierpoint (1864)
Fun ẹwa ile aye, 
Fun ogo oju ọrun,
Fun ifẹ to yi wa ka 
Lati 'gba t'a ti bi wa;
Krist' Oluwa, Iwọ la fi
Orin iyin wa yii fun. 

Fun iyanu wakati 
Ọjọọjọ at' alaalẹ,
Oke, 'lẹ, igi, ododo
Orun, oṣupa 'rawọ;
Krist' Oluwa, Iwọ la fi
Orin iyin wa yii fun.

Fun ayo eti, oju,
Fun idunnu okan wa
Fun irepo adiitu
T'ori, riri o'n gbigbo
Krist' Oluwa, Iwọ la fi
Orin iyin wa yii fun.

Fun ayọ ifẹ eeyan, 
Ọmọ 'ya, obi, ọmọ, 
Ọrẹ aye, ọrẹ oke, 
Fun gbogbo ero tutu;
Krist' Oluwa, Iwọ la fi
Orin iyin wa yii fun.

Fun 'jọ Rẹ t'o n gbe ọwọ 
Mimọ soke titi lai
Nibi gbogbo t'o n rubọ, 
Irubọ ifẹ pipe;
Krist' Oluwa, Iwọ la fi
Orin iyin wa yii fun.

Translated by Ayobami Temitope Kehinde on 16/02/2022








For the beauty of the earth 
For the glory of the skies, 
For the love which from our birth 
Over and around us lies.
Christ our Lord, to Thee we raise, 
This our hymn of grateful praise.

For the beauty of each hour, 
Of the day and of the night, 
Hill and vale, and tree and flower, 
Sun and moon, and stars of light.
Christ our Lord, to Thee we raise, 
This our hymn of grateful praise.

For the joy of ear and eye, 
For the heart and mind’s delight, 
For the mystic harmony 
Linking sense to sound and sight.
Christ our Lord, to Thee we raise, 
This our hymn of grateful praise.

For the joy of human love, 
Brother, sister, parent, child, 
Friends on earth and friends above, 
For all gentle thoughts and mild.
Christ our Lord, to Thee we raise, This our hymn of grateful praise.

For Thy Church, that evermore 
Lifteth holy hands above, 
Offering up on every shore 
Her pure sacrifice of love.
Christ our Lord, to Thee we raise, This our hymn of grateful praise.

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na