Jesu to Lewa Ju/ Fairest Lord Jesus
Author: Unknown
Jesu to lẹwa ju, adari ẹda gbogbo Ọm' Ọlọrun at' Ọmọ eeyan N o mọ riri Rẹ, n o bu ọla fun Ọ 'Wọ, ogo, ayọ, ade ọkan mi. Didara lawọn ọdan, sibẹ igi 'gbo dara ju Ta wọ pel' ogo igba 'ruwe Jesu dara julọ, Jesu funfun julọ O mọkan 'banujẹ kọrin Didara ni oorun, sibẹ oṣupa dara ju, Ati awọn irawọ ti n tan Jesu mọlẹ ju wọn, Jesu tan ju wọn lọ Ju gbogbo angẹli ni ọrun Olugbala arẹwa, Oluwa ilẹ gbogbo, Ọm' Ọlọrun at' Ọmọ eeyan! Ogo ati ọla, iyin ati' juba, Ko jẹ Tirẹ titi lailai. Translated by Ayọbami Temitọpẹ Kẹhinde on 3rd April, 2024 | Fairest Lord Jesus, ruler of all nature O thou of God and man the Son
Thee will I cherish, Thee will I honour Thou, my soul's glory, joy, and crown Fair are the meadows, fairer still the woodlands
Robed in the blooming garb of spring
Jesus is fairer, Jesus is purer Who makes the woeful heart to sing
Fair is the sunshine, fairer still the moonlight And all the twinkling starry host Jesus shines brighter, Jesus shines purer Than all the angels heaven can boast. Beautiful Saviour! Lord of all the nations Son of God and Son of Man
Glory and honour, praise, adoration Now and forevermore be thine Source: Hymn Site
|
Comments
Post a Comment