Ki N Le Rin Sun Mọ Ọ Sii / Just A Closer Walk With Thee
Author: Unknown
Mo ṣaarẹ, O lagbara Jesu gba mi lọw’ ẹṣẹ N o nitẹlọrun n’wọn ’gba Mo ba Ọ rin, jẹ ki n le ba Ọ rin Egbe: Ki n le rin sun mọ Ọ sii Jesu, f’ ẹ̀bẹ̀ yii fun mi Ki n ba Ọ rin lojumọ Je ko ṣẹ, Oluwa, je ko ṣẹ Laye 'ṣẹ́, ìkẹkùn yii Tí m' ba kùnà ta lo kan? Ta ló ń bá mi gbẹ́rù mi Kò sí o, Oluwa, Ìwọ ni. ’Gbà ’yé àíléra mi pin Tí ’gba mi láyé dópin Tọ́jú mi títí délé ’Jọba Rẹ̀, àní ìjọba Rẹ Translated by Ayobami Temitope Kehinde on 20/05/2024 | I am weak but Thou art strong;
Jesus, keep me from all wrong;
I'll be satisfied as long
As I walk, let me walk close to Thee.
Refrain:
Just a closer walk with Thee,
Grant it, Jesus, is my plea,
Daily walking close to Thee,
Let it be, dear Lord, let it be.
Thro' this world of toil and snares,
If I falter, Lord, who cares?
Who with me my burden shares?
None but Thee, dear Lord, none but Thee. [Refrain]
When my feeble life is o'er,
Time for me will be no more;
Guide me gently, safely o'er
To Thy kingdom shore, to Thy shore. [Refrain]
Source: Baptist Hymnal, 1991
|
Comments
Post a Comment