Si Ọ Olutunu Ọrun/To Thee, O Comforter Divine
Author: Frances R. Havergal
1. Si Ọ Olutunu Ọrun Fun ore at’agbara Rẹ A n ko, a n ko, a n ko aleluyah! 2. Si O, ife eni t’O wa Ninu Majemu Olorun A n ko, a n ko, a n ko aleluya 3. Si O agbara Eni ti O nwe ni mo, t’o nwo ni san A n ko, a n ko, a n ko aleluya 4. Si O, Olukọ at’ore Amona wa toto d’opin A n ko, a n ko, a n ko aleluya 5. Si O, Ẹni ti Kristi ran Ade o'n gbogbo ebun Rẹ A n ko, a n ko, a n ko aleluya. Amin. | 1. To thee, O Comforter divine, for all thy grace and power benign, Sing we Alleluia! Alleluia! 2. To thee, whose faithful love had place in God's great covenant of grace, Sing we Alleluia! Alleluia! 3. To thee, whose faithful power doth heal, enlighten, sanctify, and seal, Sing we Alleluia! Alleluia! 4. To Thee, our teacher and our friend,
Our faithful leader to the end,
Sing we Alleluia! Alleluia! 5. To thee, by Jesus Christ sent down, of all his gifts the sum and crown, Sing we Alleluia! Alleluia! Source: CPWI Hymnal #297 |
Comments
Post a Comment