'Bi 'Sadi Nla L'Olorun Wa / A Mighty Fortress is Our God
Author: Martin Luther (1529)
'Bi'sadi nla l'Ọlọrun wa, Odi wa ti ko le yẹ; Olùrànlọ́wọ́ n'nu igbi, Idanwo to yi wa ka 'Tori ọta 'gba nni, Tun fẹ ṣe wa n'ibi; Agbara re si pọ, Pẹlu ikorira, Ko s'iru rẹ ni aye yi. A ko gbẹkẹl' agbara wa, Tori yo ja wa kulẹ Ti ko ba si pe Ẹni naa, Ti Ọlọrun yan fun wa O fẹ m'Ẹni naa bi? Jesu Kristi ni iṣe Oluwa Ologun, Ẹni ayeraye, Yoo si ṣẹgun ni dandan. B'ẹmi aimọ ni gbogb'aye, N halẹ lati bo wa mọlẹ; A ki o bẹru 'tor'Ọlọrun Fẹ ṣẹgun nípasẹ̀ wa; Ọm' alade okunkun, Ẹ̀rù rẹ̀ ko ba wa A o bori 'runu rẹ Iparun rẹ daju Ọr' Ọlọ́run yoo bii ṣubu Ọrọ yẹn ju agbara aye lọ, Ṣíọ̀ sí wọn, o wa titi, Ẹ̀mí at' awọn ẹ̀bùn Rẹ̀ Jẹ tiwa nipasẹ Jesu. Ẹrù, ará lè lọ, At' ara kiku yìí Won le pa ara yìí: Oot' Ọlọ́run sì wà Ìjọba Rẹ̀ wà títí láí. Source: Hymnaro #703 (Some adjustments made in the translation by me, Ayobami Temitope Kehinde) | A mighty fortress is our God, a bulwark never failing; our helper he, amid the flood of mortal ills prevailing. For still our ancient foe does seek to work us woe; his craft and power are great, and armed with cruel hate, on earth is not his equal. Did we in our own strength confide, our striving would be losing, were not the right Man on our side, the Man of God's own choosing. You ask who that may be? Christ Jesus, it is he; Lord Sabaoth his name, from age to age the same; and he must win the battle. And though this world, with devils filled, should threaten to undo us, we will not fear, for God has willed his truth to triumph through us. The prince of darkness grim, we tremble not for him; his rage we can endure, for lo! his doom is sure; one little word shall fell him. That Word above all earthly powers no thanks to them abideth; the Spirit and the gifts are ours through him who with us sideth. Let goods and kindred go, this mortal life also; the body they may kill: God's truth abideth still; his kingdom is forever! |
Comments
Post a Comment