Iwo ha n'idakoro t'o daju?
Ninu irumi at'iji aiye
Nigbati ikun omi ba dide
Idakoro re ha le duro?
Egbe
Idakoro mbe fun okan wa
B'o ti wu ki iji na le to
Jesu l'Apata ti ko le ye
Lor' Apata ife Re l'a nduro
A ti gunle s'ebute isimi
Ko s' ewu a mbe lowo Oluwa
Okun ife t'o fi fa wa mora
Kosi iji ti o le fa ja
A duro sinsin kosi eru mo
Awon ota wa ni oju y'o ti
Kosi igbi t'o le ba wa l'eru
Awa n'idakoro t'o daju
Bi a tile nrin l'ojiji iku
Riru omi ko le bo wa mole
Krist' Apata wa y'o mu wa laja
On ni idakoro 'reti wa
'Gbat' a ba yoju sinu Ogo nla
Si ebute ti a fi wura ko
A o duro lori idakoro wa
Gbogbo iji y'o re wa koja.
Amin
| Will your anchor hold in the storms of life, When the clouds unfold their wings of strife? When the strong tides lift, and the cables strain, Will your anchor drift or firm remain? Refrain We have an anchor that keeps the soul Stedfast and sure while the billows roll, Fastened to the Rock which cannot move, Grounded firm and deep in the Savior’s love. It is safely moored, ’twill the storm withstand, For ’tis well secured by the Savior’s hand; And the cables passed from His heart to mine, Can defy the blast, through strength divine.
It will firmly hold in the straits of fear, When the breakers have told the reef is near; Though the tempest rave and the wild winds blow, Not an angry wave shall our bark o’erflow. It will surely hold in the floods of death, When the waters cold chill our latest breath; On the rising tide it can never fail, While our hopes abide within the veil.
|
Comments
Post a Comment