O n Mu Mi Korin/He Keeps Me Singing



Author: Luther B. Bridgers, 1910

Orin kan wa ninu ọkan mi
Jesu sọ fun mi wuyẹ
"Ma ṣe bẹru, Mo wa pelu rẹ,
Loke lodo ni aye"

Egbe

Jesu, Jesu, Jesu,
Orukọ to dun ju
Mu 'fẹ ọkan mi ṣẹ
Mu mi kọrin bi mo ti n lọ

Ẹṣẹ, ija maye mi daru
Arankan kun ọkan mi
Jesu so okun to ja papọ
Ta okun orin to sun ji

Mo n ṣ' àsè n'nu ọrọ or'-ọfẹ Rẹ
Mo n sinmi labẹ 'yẹ Rẹ
Mo n woju ẹrin Rẹ kikankikan
Tor' eyi ni mo n kọrin 

B'O tilẹ mu ọ la omi kọja
Idamu wa lọna rẹ
Bọna rẹ ko gun to si ṣoro
R' ipasẹ Rẹ lọna rẹ

Laipẹ, O n bọ lati gba mi sílé
Ni ọrun jina réré
N o fo lọ s’oke, aye àìmọ̀
N o ba jọba loke

Translated by Ayobami Temitope Kehinde 
on 05 August, 2025



There’s within my heart a melody
Jesus whispers sweet and low,
“Fear not, I am with thee, peace, be still,”
In all of life’s ebb and flow.

Refrain:

Jesus, Jesus, Jesus,
Sweetest Name I know,
Fills my every longing,
Keeps me singing as I go.

All my life was wrecked by sin and strife,
Discord filled my heart with pain,
Jesus swept across the broken strings
Stirred the slumb’ring chords again.

Feasting on the riches of His grace,
Resting ’neath His shelt’ring wing,
Always looking on His smiling face,
That is why I shout and sing.

Though sometimes He leads through waters deep,
Trials fall across the way,
Though sometimes the path seems rough and steep,
See His footprints all the way

Soon He’s coming back to welcome me,
Far beyond the starry sky;
I shall wing my flight to worlds unknown,
I shall reign with Him on high.

Source: Timeless Truths

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na