Posts

Okan Mi Yo Ninu Oluwa

Author: E.O. Excell Okan mi nyo ninu Oluwa ‘Tori O je iye fun mi Ohun Re dun pupo lati gbo Adun ni lati r’oju Re Emi yo ninu Re Emi yo ninu Re Gba 'gbogbo lo fayo kun okan mi ‘Tori emi nyo n’nu Re. O ti pe t’O ti nwa mi kiri ‘Gbati mo rin jina s’agbo O gbe mi wa sile l’apa Re Nibiti papa tutu wa Ire at’anu Re yi mi ka Or’ofe Re n san bi odo Emi Re nto, o si nse ‘tunu O n ba mi lo si ‘bikibi Emi y’o dabi Re ni ‘jo kan N o s’eru wuwo mi kale Titi di ‘gbana n o s’oloto Ni sise oso f’ade Re. Amin. Translated by Ayobami Temitope Kehinde Dec 15, 2018. My soul is so happy in Jesus, For He is so precious to me; His voice it is music to hear it, His face it is heaven to see. Refrain: I am happy in Him, I am happy in Him; My soul with delight He fills day and night, For I am happy in Him. He sought me so long ere I knew Him, When wand’ring afar from the fold; Safe home in His arms He hath bro't me, To where there...

Alleluya! Ija D’opin, Ogun Si Tan

Author Unknown Trans f. Latin to English: Francis Pott Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d’opin ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo lao ma ko. – Alleluya! Gbogbo ipa n’iku ti lo; Sugbon Kristi f’ogun re ka; Aye ! e ho iho ayo. – Alleluya! Ojo meta na ti koja. O jinde kuro nin’oku: E f’ogo fun Olorun wa. – Alleluya! O d’ewon orun apadi, O silekun orun sile; Ekorin iyin ‘segun Re. – Alleluya! 5. Jesu, nipa iya t’O je, A bo lowo iku titi: Titi la o si ma yin O – Alleluya! Alleluia, alleluia, alleluia! The strife is o'er, the battle done, the victory of life is won; the song of triumph has begun. Alleluia! The powers of death have done their worst, but Christ their legions hath dispersed: let shout of holy joy outburst. Alleluia! The three sad days are quickly sped, he rises glorious from the dead: all glory to our risen Head! Alleluia! He closed the yawning gates of hell, the bars from heaven's high portals fell; let h...

E YO N’NU OLUWA, E YO

Words:Mary E. Servoss, in Sacred Songs and Solos, by Ira D. Sankey, 1881. E yo n’nu Oluwa, e yo, Eyin t’okan re se dede Eyin t’o ti yan Oluwa, Le ‘banuje at’aro lo Refrain: Eyo! E yo! E yo n’nu Oluwa, e yo! E yo! E yo! E yo n’nu Oluwa, e yo! E yo ‘tori O'n l’Oluwa L’aye ati l’orun pelu Oro Re bor’ohun gbogbo O l’agbara lati gbala ‘Gbat’ e ba nja ija rere, Ti ota f’ere bori yin Ogun Olorun t’e ko ri Po ju awon ota yin lo B’okunkun tile yi o ka Pelu isudede gbogbo Mase je k’okan re damu Sa gbeke l’Oluwa d’opin E yo n’nu Oluwa, e yo E korin iyin Re kikan Fi duru ati ohun ko Aleluya l’ohun goro. Amin. Be glad in the Lord, and rejoice, All ye that are upright in heart; And ye that have made Him your choice, Bid sadness and sorrow depart. Rejoice, rejoice, Be glad in the Lord and rejoice; Rejoice, rejoice, Be glad in the Lord and rejoice Be joyful, for He is the Lord, On earth and in Heaven supreme; He fashions and rules by His word— The ...

ASEGUN ATI AJOGUN NI A JE

Image
Author: Mrs C.H. Morris A segun ati ajogun ni a je, Nipa eje Kristi a ni isegun B’Oluwa je tiwa, a ki yo subu Ko s’ohun to le bori agbara re Asegun ni wa, nipa eje Jesu Baba fun wa ni ‘segun, nipa eje Jesu Eni t’a pa f’elese Sibe, O wa, O njoba Awa ju asegun lo Awa ju asegun lo A nlo l’oruko Olorun Isreal Lati segun ese at’aisododo Kise fun wa, sugbon Tire ni iyin Fun ‘gbala at’isegun ta f’eje ra Eni t’O ba si segun li ao fi fun Lati je manna to t’orun wa nihin L’orun yo sig be imo ‘pe asegun Yo wo ‘so funfun, yo si dade wura. Amin Conquerors and overcomers now are we, Thro’ the precious blood of Christ we've victory, If the Lord be for us, we can never fail; Nothing 'gainst his mighty pow'r can e'er prevail. Conquerors are we, thro’ the blood, thro’ the blood; God will give us victory, thro’ the blood, thro’ the blood, Thro’ the Lamb for sinners slain, Yet who lives and reigns again, More than conquerors are we, More than conqueror...

OGO F'OLORUN ALLELUIA!

Words: Fanny Crosby Ko su wa lati ma ko orin ti igbani Ogo f’olorun Alleluia! A le fi igbagbo korin na s’oke kikan Ogo f’olorun Alleluia! Omo olorun ni eto lati ma bu s’ayo Pe ona yi nye wa si, Okan wa ns’aferi Re Nigb’o se a o de afin Oba wa ologo,  Ogo f’olorun Alleluia! Awa mbe n’nu ibu ife t’o ra wa pada, Ogo f’olorun Alleluia! Awa y’o fi iye goke lo s’oke orun Ogo f’olorun Alleluia! Awa nlo si afin kan ti a fi wura ko, Ogo f’olorun Alleluia! Nibiti a ori Oba ogo n’nu ewa Re Ogo f’olorun Alleluia! Nibe ao korin titun t’anu t’o da wa nde Ogo f’olorun Alleluia! Nibe awon ayanfe yo korin 'yin ti Krist; Ogo f’olorun Alleluia! We are never, never weary Of the grand old song; Glory to God, hallelujah! We can sing it loud as ever, with our faith more strong; Glory to God, hallelujah! O, the children of the Lord Have a right to shout and sing, For the way is growing bright, And our souls are on the wing; We are going by and by To the palace...

OJO NLA

Words: Philip Doddridge, refrain from Wesleyan Sacred Harp Ojo ayo l’ ojo ti mo Yan O, 'Wo Olugbala mi; O to ki okan mi ko yo, K’o si sayo re kakiri. Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki n ma gbadura Ki nma sora ki nsi ma yo Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu. A ti pari ise nla naa Emi t'Oluwa O'n temi O fa mi mo si tele O Mo yo lati gba ipe naa. Simi aisokan, okan mi, Simi lori ipinnu yi; Mo ripa to lola nibi, Ayo orun kun mi laya. Orun giga to gbeje mi, Yoo gbo lotun lojojumo, Titi n o fi fibukun fun, Idapo yi loju iku. O happy day, that fixed my choice On Thee, my Savior and my God! Well may this glowing heart rejoice, And tell its raptures all abroad. Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! He taught me how to watch and pray, And live rejoicing every day: Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! O happy bond, that seals my vows To Him Who merits all my love! Let cheerful an...

A Fope F'Olorun

Words:Martin Rinkart, circa 1636 (Nun danket alle Gott); first appeared in Praxis Pietatis Melica, by Johann Crüger (Berlin, Germany: 1647); translated from German to English by Catherine Winkworth, 1856 . A fope f'Olorun lokan ati lohun wa: Eni sohun 'yanu, n'nu Eni taraye n yo. Gba ta wa lomo'wo, Oun na lo n toju wa, O si febun ife se'toju wa sibe. Oba Onibuore, ma fi wa sile lailai, Ayo ti ko lopin oun 'bukun yoo je tiwa. Pa wa mo ninu ore, to wa 'gba ba damu, Yo wa ninu ibi laye ati lorun. Ka fiyin oun ope f'Olorun Baba, Omo Ati Emi Mimo ti O ga julo lorun Olorun kan lailai taye atorun n bo Bee l'O wa d'isinyi,  beeni y'O wa lailai. Now thank we all our God, with heart and hands and voices, Who wondrous things has done, in whom this world rejoices; Who from our mothers’ arms has blessed us on our way With countless gifts of love, and still is ours today. O may this bounteous God through all our life be near us, ...