Ija D'opin, Ogun Si Tan
 Author Unknown  Translated from Latin to English by Francis Pott      Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!!  Ija d' opin, ogun si tan:  Olugbala jagun molu:  Orin ayọ l' a o ma kọ.  Alleluya!   Gbogbo ipa n' iku si lo: Ṣugbọn Kristi f' ogun rẹ ka:  Aye ẹ ho iho ayọ - Alleluya!  Ọjọ mẹta na ti kọja.  O jinde kuro nin' oku: Ẹ f' ogo fun Ọlọrun wa. -Alleluya!   O d' ẹwọn ọrun apadi,  O s' ilẹkun ọrun silẹ:  E kọrin iyin 'ṣẹgun Re. - Alleluya!   Jesu nipa iya t' O jẹ,  A bọ lọwọ iku titi:  Titi l' a o si ma yin Ọ. - Alleluya!   Source: Yoruba Baptist Hymnal #123     Alleluia, alleluia, alleluia!  The strife is o'er, the battle done,  the victory of life is won;  the song of triumph has begun.   Alleluia!   The powers of death have done their worst,  but Christ their legions hath dispersed:  let shout of holy joy outburst.  Alleluia!   The three sad days are quickly sped,  he rises glorious from the dead:  all glory to our risen Head!  Alleluia!  ...