Jesu O Seun/ Jesus Thank You
 Writer:Pat Sczebel       Adiitu agbelebu ko ye mi sibẹ,  Irora ti Kalfari--  Ìwọ t'O pe t'O si mọ lu Ọmọ Rẹ  T'O m'ago ikoro to yẹ ki n mu.   Chorus  Ẹ̀jẹ̀ Rẹ ti wẹṣẹ mi nu,  Jesu O seun.  Irunu Ọlọrun walẹ pata,  Jesu O seun.  Mo ti jọta Rẹ ri,  Wayi mo n ba Ọ jeun,  Jesu O seun.   Nipa 'rubọ pipe Rẹ la fi fa mi,  O s' ọta Rẹ dọrẹ Rẹ;  Ọrọ or'ọfẹ ologo Rẹ lo tu jade,  Aanu at' inu're Rẹ ko lopin.   Bridge  Olufẹ́ ọkan mi,  Mo fẹ́ ma wa fun Ọ.   Translated by Ayobami Temitope  Kehinde (21/04/2017) The mystery of the cross I cannot comprehend  The agonies of Calvary--  You the perfect Holy One, crushed Your Son,  Who drank the bitter cup reserved for me.   CHORUS  Your blood has washed away my sin  Jesus, thank You  The Father’s wrath completely satisfied  Jesus, thank You  Once Your enemy, now seated at Your table  Jesus, thank You   By Your perfect sacrifice I’ve been brought near,  Your enemy You’ve made Your friend;  Pouring out the riches of Yo...