Posts

FREE MUSIC DOWNLOAD

Hi friends, I just released three singles. You can download them free of charge from this link:   www.reverbnation.com/ preciousay

ISUN KAN WA

William Cowper, 1731-1800 Isun kan wa to kun feje, O yo niha Jesu. Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi. Gba mo figbagbo risun naa, Ti n san fun ogbe Re, Irapada dorin fun mi Ti n o ma ko titi. Ninu orin to dun ju lo, Lemi o korin Re: 'Gba t'akololo ahon yii Ba dake niboji. Mo gbagbo p'O pese fun mi (Bi mo tile saiye) Ebun ofe ta feje ra, Ati duru wura. Duru ta towo'Olorun se, Ti ko ni baje lai: T'a o ma fi yin Baba wa, Oruko Re nikan. Source: YB Hymnal #232 There is a fountain filled with blood, Drawn from Immanuel’s veins, And sinners plunged beneath that flood Lose all their guilty stains: The dying thief rejoiced to see That fountain in His day; And there may I, though vile as he, Washed all my sins away: Dear dying Lamb, Thy precious blood Shall never lose its pow’r, Till all the ransomed church of God Are safe, to sin no more: E’er since by faith I saw the stream Thy flowing wounds supply, Redeeming love has been

IGBAGBO MI DURO LORI

By Edward Mote Igbagbo mi duro lori Eje atododo Jesu N'ko je gbekele ohun kan Leyin oruko nla Jesu Mo duro le Krist' apata Ile miran, iyanrin ni B'ire ije mi tile gun Ore-ofe Re ko yi pada Bo ti wu k'iji na le to Idakoro mi ko ni ye Mo duro le Krist' apata Ile miran iyanrin ni Majemu ati eje Re L'emi o ro mo b'ikunmi de Gbati ohun aye bo tan O je ireti nla fun mi Mo duro le Krist' apata Ile miran iyanrin ni Gbat'ipe kehin ba si dun A! m ba le wa lodo Jesu Ki nwo ododo Re nikan Ki n duro niwaju ite Mo duro le Krist' apata Ile miran iyanrin ni My hope is built on nothing less Than Jesus’ blood and righteous; No merit of my own I claim But wholly lean on Jesus’ name. On Christ, the solid rock, I stand; All other ground is sinking sand. When darkness veils his lovely face, I ret on his unchanging grace; In every high and story gale My anchor holds within the veil. On Christ, the solid rock, I stand; All oth

MO TI NI JESU LORE

By  William Charles Fry (1837–1882) Mo ti ni Jesu lore O j'ohun gbogbo fun mi Oun nikan larewa ti okan mi fe Oun nitanna ipado Oun ni Enikan naa To le we mi nu kuro nin'ese mi Olutunu mi lo je ni gbogbo wahala Oun ni ki n kaniyan mi l'Oun lori Oun n'Itanna Ipado Irawo Owuro Oun nikan l'Arewa ti okan mi fe Olutunu mi lo je ni gbogbo wahala Oun ni ki n kaniyan mi l'Oun lori Oun n'Itanna Ipado Irawo Owuro Oun nikan l'Arewa ti okan mi fe O gbe gbogbo banuje At'irora mi ru O j'Odi agbara mi n'gba danwo Tori Re mo k'ohun gbogbo Ti mo ti fe sile O si f'agbara Re gbe okan mi ro Bi aye tile ko mi Ti Satan' dan mi wo Jesu yoo mu mi d'opin irin mi Oun n'Itanna ipado Irawo Owuro Oun nikan l'Arewa ti okan mi fe Oun ki yo fi mi sile Be ki yo ko mi nihin Niwon ti m'ba figbagbo pofin Re mo O jodi ina yi mi ka N k'y'o beru-keru Y'o fi manna Re bokan mi t'ebi npa Gba m'b

ENI KAN NBE TO FERAN WA

Author: Marianne Nunn (1778-1847) Enikan nbe to feran wa A! O fe wa! Ife Re ju t'iyekan lo A! O fe wa! Ore aye nko wa sile Boni dun, ola le koro Sugbon Ore yi ki ntan ni A! O fe wa! Iye ni fun wa ba ba mo A! O fe wa! Ro, ba ti je ni gbese to A! O fe wa! Eje Re lo si fi ra wa Nin'aginju l'O wa wa ri O si mu wa wa sagbo Re A! O fe wa! Ore ododo ni Jesu A! O fe wa! O fe lati ma bukun wa A! O fe wa! Okan wa fe gbo ohun Re Okan wa fe lati sunmo Oun na ko si ni tan wa ke A! O fe wa! Oun lo je ka ridariji A! O fe wa! Oun o le ota wa sehin A! O fe wa! Oun o pese 'bukun fun wa Ire la o ma ri titi Oun o fi mu wa lo sogo A! O fe wa! One is kind above all others, Oh, how He loves! His is love beyond a brother’s, Oh, how He loves! Earthly friends may fail or leave us, One day soothe, the next day grieve us; But this Friend will ne’er deceive us: Oh, how He loves! ’Tis eternal life to know Him, Oh, how He loves! Think, oh, think how

MO TI SELERI JESU

By John Ernest Bode (February 13, 1816 – October 6, 1874) Mo ti seleri Jesu Lati sin O dopin Ma wa lodo mi titi Baba mi Ore mi Emi k'yo beru ogun B'Iwo ba sun mo mi Emi ki yo si sina B'O ba fona han mi Je ki n mo p'O sunmo mi 'Tori'baje aye Aye fe gba okan mi Aye fe tan mi je Ota yi mi kakiri Lode ati ninu Sugbon Jesu sunmo mi Dabo bo okan mi Je ki emi ko ma gbo Ohun Re, Jesu mi Ninu igbi aye yi Titi nigbagbogbo So ko fokan mi bale Te 'ri okan mi ba So kemi le gbo Tire 'Wo Olutoju mi 'Wo ti seleri Jesu F'awon to tele O Pe ibikibi t'O wa Lawon yoo si wa Mo ti seleri Jesu Lati sin O dopin Je ki n ma to O lehin Baba mi, Ore mi Je ki n ma ripase Re Ki n le ma tele O Agbara Re nikan ni Ti m' ba le tele O To mi, pe mi, si fa mi Di mi mu de opin Si gba mi si odo Re Baba mi, Ore mi O Jesus, I have promised To serve Thee to the end; Be Thou forever near me, My Master and my Friend; I shall not

GBA AYE MI OLUWA

Frances Ridley Havergal (1874) Gba aye mi, Oluwa Mo ya si mimo fun O Gba gbogbo akoko mi Ki won kun fun iyin re Gba owo mi ko si je Ki n ma lo fun ife Re Gba ese mi ko si je Ki won ma sare fun O Gba ohun mi je ki n ma Korin f'Oba mi titi Gba ete mi, je ki won Ma jise fun O titi Gba wura, fadaka mi Okan nki o da duro Gba ogbon mi, ko si lo Gege bi o ba ti fe Gba 'fe mi fi se Tire Ki yo tun je temi mo Gbokan mi, Tire ni se Ma gunwa nibe titi Gba feran mi, Oluwa Mo fi gbogbo re fun O Gbemi paapa latoni Ki n je Tire titi lai. Take my life and let it be Consecrated, Lord, to Thee. Take my moments and my days, Let them flow in endless praise. Take my hands and let them move At the impulse of Thy love. Take my feet and let them be  Swift and beautiful for Thee.  Take my voice and let me sing, Always, only for my King.  Take my lips and let them be  Filled with messages from Thee.  Take my silver and my gold,  Not a mite would I withho