Posts

Ija D'opin, Ogun Si Tan

Author Unknown Translated from Latin to English by Francis Pott Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d' opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo l' a o ma ko. Alleluya! Gbogbo ipa n' iku si lo: Sugbon Kristi f' ogun re ka: Aiye E ho iho ayo - Alleluya! Ojo meta na ti koja. O jinde kuro nin' oku: E f' ogo fun Olorun wa. -Alleluya! O d' ewon orun apadi, O s' ilekun orun sile: E korin iyin 'segun Re. - Alleluya! Jesu nipa iya t' O je, A bo lowo iku titi: Titi l' a o si ma yin O. - Alleluya! Source: Yoruba Baptist Hymnal #123 Alleluia, alleluia, alleluia! The strife is o'er, the battle done, the victory of life is won; the song of triumph has begun.  Alleluia! The powers of death have done their worst, but Christ their legions hath dispersed: let shout of holy joy outburst. Alleluia! The three sad days are quickly sped, he rises glorious from the dead: all glory to our risen Head! Allelui

Jesu Ye Titi Aye

Words: Christian Friedrich Gellert (1715-1769), 1757 Translated by Frances E. Cox (1812-1897), 1841 Tune: St Albinus Jesu ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n 'ipa mo. - Alleluya! Jesu ye; lat' oni lo Iku je ona si iye; Eyi y'o je ' tunu wa 'Gbat' akoko iku ba de. - Alleluya! Jesu ye; fun wa l' O ku; Nje Tire ni a o ma se; A o f'okan funfun sin, A o f'ogo f'Olugbala. - Alleluya! Jesu ye; eyi daju, Iku at' ipa okunkun Ki y'o le ya ni kuro Ninu ife nla ti Jesu. - Alleluya! Jesu ye; gbogbo 'joba L'orun, li aiye, di Tire; E ja ki a ma tele Ki a le joba pelu Re. - Alleluya. Source: Yoruba Baptist Hymnal #125 Jesus lives! thy terrors now can no more, O death, appal us; Jesus lives! by this we know thou, O grave, canst not enthrall us. Alleluia! Jesus lives! henceforth is death but the gate of life immortal; this shall calm our trembling breath when we pass its gloomy

Jesu N Pe WA L'osan l'oru

Image
Author: Cecil Frances Alexander (1852) Jesu npe wa l' osan, l' oru Larin irumi aiye; Lojojumo l' a ngb' ohun Re Wipe, "Kristian, tele Mi." Awon Apostili 'gbani, Ni odo Galili ni; Nwon ko ile, ona sile, Gbogbo nwon si nto lehin. Jesu npe wa larin lala Aiye wa buburu yi; Larin Afe aiye, O nwi Pe, "Kristian, e feran Mi." Larin ayo at' ekun wa, Larin 'rora on osi, Tantan L' O npe l' ohun rara Pe, "Kristian, e feran Mi." Olugbala, nip' anu Re, Je ki a gbo ipe Re, F' eti 'gboran fun gbogbo wa, K' a fe O ju aiye lo. Jesus calls us: o'er the tumult Of our life's wild, restless sea; Day by day his sweet voice soundeth Saying, "Christian, follow me." As, of old, apostles heard it By the Galilean lake, Turned from home and toil and kindred, Leaving all for his dear sake. Jesus calls us from the worship Of the vain world's golden store, From each idol t

Fun Wa N'le Onigbagbo

Image
Author: B.B McKinney Fun wa n’le onigbagbo Ile ti a nkeko Bibeli Ile ti a nlepa ‘fe Baba Ta f’ewa ife re de lade Fun wa n’le Onigbagbo /2ce Fun wa n’le Onigbagbo Nibi ti Baba j’olotito Ile t’o t’akete si ibi Ile t’o kun f’ayo ‘fe at’orin Fun wa n’le onigbagbo /2ce Fun wa n’le Onigbagbo ‘le t’iya nsise b’oba obinrin Fihan p’ona re lo dara ju Ile ti ngba Jesu l’alejo Fun wa n’le Onigbagbo /2ce Fun wa n’le onigbagbo Ni’bi ti an nto awon omode L’ati mo Kristi t’o feran won Ile t’ina adura tin jo Fun wa n’le onigbagbo /2ce *From Hymn Book for All Churches in Africa: Yoruba & English with Halleluyah Chorus Aroyehun Edition. God, give us Christian homes! Homes where the Bible is loved and taught, Homes where the master’s will is sought, Homes crowned with beauty thy love hath wrought; God, give us Christian homes; God, give us Christian homes! God, give us Christian homes! Homes where the father is true and strong, Homes that are free from the blig

A O Sise!

Words: Fanny J Crosby, 1869 Music: W. Howard Doane, 1871 A o sise ! A o sise! Om'Olorun ni wa, Jek' a tele ona ti Oluwa wa to; K' a f' imoran Re so agbara wa d' otun, K' a fi gbogbo okun wa sise t' a o se. Refrain: Foriti ! Foriti ! Foriti ! Foriti ! K' a reti, k' a s' ona Titi Oluwa yio fi de. A o sise ! A o sise ! Bo awon t' ebi npa, Ko awon alare lo s' orisun iye! Ninu agbalebu l' awa o ma s' ogo, Nigbat' a ba nkede pe, "Ofe n'igbala," A o sise ! A o sise ! Gbogbo wa ni yio se, Ijoba okunkun at'iro yio fo, Ao si gbe oruko Jehofah leke, won, Ninu orin iyin wa pe, "Ofe n'igbala," A o sise ! A o sise !  L'agbara Oluwa, Agbada at'ade yio si je ere wa; Ile awon oloto yio si je ti wa, Gbogbo wa o jo ho pe, "Ofe n'igbala," To the work! to the work! We are servants of God, Let us follow the path that our Master has trod; With the might of His p

Mo Fe O N'gbagbogbo

Author: An­nie S. Hawks, 1872 Mo fe O n'gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s' ohun ti nfun ni L' alafia bi Tire. Refrain: Mo fe O, a! mo fe O, Ni wakati gbogbo; Bukun mi Olugbala, Mo wa s' odo Re. Mo fe O n' gbagbogbo, Duro ti mi, Idanwo ko n' ipa Gbat' O wa nitosi. Mo fe O n' gbagbogbo, L' ayo tab' irora; Yara wa ba mi gbe, K' aiye mi ma j' asan. Mo fe O n'gbagbogbo, Ko mi ni ife Re; K' O je k'ileri Re Se si mi li ara. Mo fe O n'gbagbogbo, Ologo julo; Se mi n' Tire toto, Omo alabukun. I need Thee every hour, Most gracious Lord; No tender voice like Thine can peace afford. Refrain I need Thee, O I need Thee; Every hour I need Thee; O bless me now, my Savior, I come to Thee. I need Thee every hour, stay Thou nearby; Temptations lose their power when Thou art nigh. I need Thee every hour, In joy or pain; Come quickly and abide, Or life is in vain. I need Thee every

Mo N Tesiwaju Lona Na

Author: Johnson Oatman Jr (1856-1952) Mo n te siwaju lona na Mo n goke si lojojumo Mo n gbadura bi mo ti n lo Oluwa jo gbe mi soke Refrain: Oluwa jo gbe mi soke Fami lo si ibi giga Apata to ga jumi lo Oluwa jo gbe mi soke Ife okan mi ko duro Larin 'yemeji at'eru Awon miran le ma gbe'be Ibi giga lokan mi fe Mo fe ki nga ju aye lo Ninu ogo didan julo Mo ngbadura ki nle de 'be Oluwa mumi de 'le na. Fa mi lo si ibi giga L’aisi Re nko ni le de 'be Fa mi titi d’oke orun Ki nkorin lat'ibi giga. I’m pressing on the upward way, New heights I’m gaining every day; Still praying as I onward bound, “Lord, plant my feet on higher ground.” Refrain: Lord, lift me up, and let me stand By faith on Canaan’s tableland; A higher plane than I have found, Lord, plant my feet on higher ground. My heart has no desire to stay Where doubts arise and fears dismay; Though some may dwell where these abound, My prayer, my aim, is higher gr