Adua Didun
Words: William W. Walford Adua didun, adua didun To gbe mi lo kuro laye, Lo'waju ite Baba mi, Ki n so gbogbo edun mi fun: Nigba'banuje ataro Adua laabo fun okan mi; Emi si bo lowo Esu 'Gbati mo ba gbadua didun. Adua didun, adua didun Iye re yo gbe ebe mi, Lo sod'Eni t'O seleri Lati bukun okan adua. Bo ti ko mi ki n woju Re Ki n gbekele, ki n si gbagbo, N o ko gbogb'aniyan mi le E Ni akoko adua didun. Adua didun, adua didun Je ki n ma r'itunu re gba Titi n o fi doke Pisgah, Ti n o rile mi lookere. N o bo ago ara sile Lati jogun ainipekun; N o korin bi mo ti n fo lo, O digbose, Adua didun. Sweet hour of prayer! sweet hour of prayer! that calls me from a world of care, and bids me at my Father's throne make all my wants and wishes known. In seasons of distress and grief, my soul has often found relief, and oft escaped the tempter's snare by thy return, sweet hour of prayer! Sweet hour of prayer! sweet hour o...