Posts

Showing posts from September, 2019

K'ore Ofe Krist' Oluwa

Image
Author: John Newton K'ore ofe Krist' Oluwa, Ife Baba ail'opin, Oju rere Emi mimo, K'o t'oke ba s'ori wa; Bayi l'a le wa n'irepo. Pel' ara wa 't' Oluwa; K'a si le ni 'dapo didun, Ayo t'aye ko le ni. May the grace of Christ our Savior and the Father's boundless love, with the Holy Spirit's favor, rest upon us from above. Thus may we abide in union with each other and the Lord, and possess, in sweet communion, joys which earth cannot afford. Amen.

Ojo Oni Lo Tan

Author: S. Baring Gould Ojo oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su. Okunkun bo ile, Awon 'rawo yo; Eranko at' eiye, Lo si 'busun won. Jesu f' orun didun, F' eni alare; Je ki ibukun Re, Pa oju mi de. Je k' omo kerekere, La ara rere; S' oloko t' ewu nwu Ni oju omi. Ma to ju alaisan, Ti ko r' orun sun; Da olosa lekun L'ona ibi won. Ninu gbogbo oru, Je k' angeli Re, Ma se oluso mi, Lori eni mi. Source: YBH #62 Gbat' ile ba si mo, Je k' emi dide, B' omo ti ko l' ese, Ni iwaju Re. Ogo ni fun Baba, Ati fun Omo, Ati f' Emi Mimo, Lai ati lailai. Now the day is over, Night is drawing nigh, Shadows of the evening Steal across the sky. Now the darkness gathers, Stars begin to peep, Birds, and beasts and flowers Soon will be asleep. Jesus, give the weary Calm and sweet repose; With Thy tend'rest blessing May o...