Iwo ha N'idakoro to Daju?/Will Your Anchor Hold?

Author: Priscilla J. Owens Iwo ha n'idakoro t'o daju? Ninu irumi at'iji aiye Nigbati ikun omi ba dide Idakoro re ha le duro? Egbe Idakoro mbe fun okan wa B'o ti wu ki iji na le to Jesu l'Apata ti ko le ye Lor' Apata ife Re l'a nduro A ti gunle s'ebute isimi Ko s' ewu a mbe lowo Oluwa Okun ife t'o fi fa wa mora Kosi iji ti o le fa ja A duro sinsin kosi eru mo Awon ota wa ni oju y'o ti Kosi igbi t'o le ba wa l'eru Awa n'idakoro t'o daju Bi a tile nrin l'ojiji iku Riru omi ko le bo wa mole Krist' Apata wa y'o mu wa laja On ni idakoro 'reti wa 'Gbat' a ba yoju sinu Ogo nla Si ebute ti a fi wura ko A o duro lori idakoro wa Gbogbo iji y'o re wa koja. Amin Will your anchor hold in the storms of life, When the clouds unfold their wings of strife? When the strong tides lift, and the cables strain, Will your anchor drift or firm remain? Refrain We have...