Adua Didun
 Words: William W. Walford     Adua didun,  adua didun  To gbe mi lo kuro laye,  Lo'waju ite Baba mi,  Ki n so gbogbo edun mi fun:  Nigba'banuje ataro  Adua laabo fun okan mi;  Emi si bo lowo Esu  'Gbati mo ba gbadua didun.   Adua didun,  adua didun  Iye re yo gbe ebe mi,  Lo sod'Eni t'O seleri  Lati  bukun okan adua.  Bo ti ko mi ki n woju Re  Ki n gbekele,  ki n si gbagbo,  N o ko gbogb'aniyan mi le E  Ni akoko adua didun.   Adua didun,  adua didun  Je ki n ma r'itunu re gba  Titi n o fi doke Pisgah,  Ti n o rile mi lookere.  N o bo ago ara sile  Lati jogun ainipekun;  N o korin bi mo ti n fo lo,  O digbose,  Adua didun.  Sweet hour of prayer! sweet hour of prayer!  that calls me from a world of care,  and bids me at my Father's throne  make all my wants and wishes known.  In seasons of distress and grief,  my soul has often found relief,  and oft escaped the tempter's snare  by thy return, sweet hour of prayer!   Sweet hour of prayer! sweet hour o...