Posts

Adua Didun

Words: William W. Walford Adua didun,  adua didun To gbe mi lo kuro laye, Lo'waju ite Baba mi, Ki n so gbogbo edun mi fun: Nigba'banuje ataro Adua laabo fun okan mi; Emi si bo lowo Esu 'Gbati mo ba gbadua didun. Adua didun,  adua didun Iye re yo gbe ebe mi, Lo sod'Eni t'O seleri Lati  bukun okan adua. Bo ti ko mi ki n woju Re Ki n gbekele,  ki n si gbagbo, N o ko gbogb'aniyan mi le E Ni akoko adua didun. Adua didun,  adua didun Je ki n ma r'itunu re gba Titi n o fi doke Pisgah, Ti n o rile mi lookere. N o bo ago ara sile Lati jogun ainipekun; N o korin bi mo ti n fo lo, O digbose,  Adua didun. Sweet hour of prayer! sweet hour of prayer! that calls me from a world of care, and bids me at my Father's throne make all my wants and wishes known. In seasons of distress and grief, my soul has often found relief, and oft escaped the tempter's snare by thy return, sweet hour of prayer! Sweet hour of prayer! sweet hour o...

Eyin Ero

Image
Words: Fanny Crosby, 1859. Music: William Bradbury, 1861 Eyin ero, nibo l'e nlo T' enyin t' opa lowo nyin? A nrin ajo mimo kan lo, Nipa ase Oba wa, Lori oke on petele, A nlo s' afin Oba rere, A nlo s' afin Oba rere, A nlo s' ile t' o dara, A nlo s' afin Oba rere, A nlo s' ile t' o dara. Eyin ero, e so fun ni, T' ireti ti enyin ni? Aso mimo, ade ogo Ni Jesu y'o fi fun wa; Omi iye l' a o ma mu; A o si b' Olorun wa gbe, A o si b' Olorun wa gbe, N' ile mimo didara A o si b' Olorun wa gbe, N' ile mimo didara. E ko beru ona t' e nrin, Eyin ero kekere? Ore airi npelu wa lo, Awon Angeli yi wa ka, Jesu Kristi l' amona wa; Y'o ma so wa, y'o ma to wa, Y'o ma so wa, y'o ma to wa, Ninu ona ajo wa; Y'o ma so wa, y'o ma to wa, Ninu ona ajo wa. Ero, a le ba yin kegbe, L' ona ajo s' ile na? Wa ma kalo, wa ma kalo, Wa si egbe ero wa, Wa, e ma se fi wa s...

LOJO RE MIMO YI

Text: Elizabeth Parson, 1812-1873 Jesu, a fe pade, Lojo Re mimo yi; A si yite Re ka, Lojo Re mimo yi: 'Wo Ore wa orun, Adura wa n bo wa, Boju wo emi wa Lojo Re mimo yi. A ko gbodo lora, Lojo Re mimo yi Li eru a kunle Lojo Re mimo yi; Ma taro ise wa, K'Iwo ko si ko wa, Ka sin O bo ti ye Lojo Re mimo yi A teti soro Re Lojo Re mimo yi; Bukun oro ta gbo, Lojo Re mimo yi; Ba wa lo 'gbat'a lo, Fore igbala Re Si aya wa gbogbo, Lojo Re mimo yi.br /> Ese fi ewon de mi, Da mi, Oluwa da mi, Iwo ni n o sin titi, Jesu Olugbala mi. Jesus we love to meet On this Thy holy day We gather round Thy throne On this Thy holy day, Thou art our heavenly Friend Our prayers ascend to Thee Look on our spirits, Lord On this Thy Holy day. Let us shake off dull sloth On this Thy holy day. We kneel in reverence Lord On this Thy holy day. Our sins may Thou forgive And may Thou teach us, Lord To worship as we ought On this Thy holy day We listen t...

EMI ORUN GBADURA WA

Words: Andrew Reed, 1829 Emi orun, gbadura wa, Wa gbenu ile yi Sokale pel'agbara Re, Wa, Emi Mimo wa. Wa b'imole, si fihan wa Baini wa ti po to; Wa, to wa si ona iye, Ti olododo n rin. Wa bi ina ebo mimo: Sokan wa di mimo; Je ki okan wa je ore, Foruko Oluwa. Wa bi iri, si wa bukun Akoko mimo yi: Ki okan alaileso wa Le yo l'agbara Re. Wa bi adaba, n'apa Re, Apa ife mimo; Wa je ki ijo Re laye Dabi ijo torun. Emi orun, gbadura wa, Saye yi dile Re; Sokale pel'agbara Re, Wa, Emi Mimo wa. Spirit divine, attend our prayers, and make this house thy home; descend with all thy gracious powers, O come, great Spirit, come! Come as the light; to us reveal our emptiness and woe, and lead us in those paths of life whereon the righteous go. Come as the fire and purge our hearts like sacrificial flame; let our whole soul an offering be to our Redeemer's Name. Come as the dove, and spread thy wings, the wings of peaceful love; ...

SI PEPE OLUWA

Author Unknown Si pepe Oluwa, Mo mu 'banuje wa; 'Wo ki o fanu tewogba Ohun alaiye yi? Kristi Odaguntan Ni igbagbo mi n wo; 'Wo le ko'hun alaiye yi? 'Wo o gba ebo mi. Gba ti Jesu mi ku, A te ofin lorun; Ofin ko ba mi leru mo, Tori pe Jesu ku. To the altar of my Lord, I bring all my sorrows, Can your mercy kindly accept me, Even this living soul? Jesus Christ the Lamb of God, All time depends on You, Will You reject this my living soul? Sacrifice Thou accept When Christ died for me, The fulfilment of law The law has no more power on me, Jesus has died for me. Source: Hymnaro #590 Aroyehun ©2013

WA, EYIN OLOPE WA

Words: Henry Alford, Psalms and Hymns, 1844 Wa, eyin olope wa, Gbe orin ikore ga: Ire gbogbo ti wole Kotutu oye to de: Olorun Eleda wa Lo ti pese faini wa Wa ka rele Oloru Gbe orin ikore ga. Oko Olorun laye, Lati so eso iyin Re: Alikama at'epo N dagba faro tab'ayo Ehu na, ipe tele, Siri oka, nikehin; Oluwa 'kore, mu wa Je eso rere fun O. Nitori Olorun wa n bo Yo si kore Re sile: On o gbon gbogbo panti Kuro loko Re n'jo na; Yo fase fawon Angel' Lati gba epo sina, Lati ko alikama Si aba Re titi lai. Beeni, ma wa, Oluwa Sikore ikehin; Ko awon eniyan Re jo Kuro lese ataro: So won di mimo lailai Ki won le ma ba O gbe: Wa t'Iwo t'Angeli Re Gbe orin ikore ga.br /> Come, ye thankful people, come, raise the song of harvest home; All is safely gathered in, ere the winter storms begin. God our Maker doth provide for our wants to be supplied; Come to God’s own temple, come, raise the song of harvest home. All the world is ...

IFE ORUN

Ife orun, o ti dun to! Gbawo ni n o ri t'okan mi Y'o kun fun kiki re? Okan mi n pongbe lati mo Riri ife irapada; Ife Kristi si mi. Ife Re n'ipa ju iku; Oro Re awamaridi! Awon Angeli paapaa Wa ijinle ife yi ti. Won ko le mo iyanu na, Giga ati'bu re. Olorun nikan l'O le mo, I ba je tan kale loni; L'okan okuta yi! Ife nikan ni mo n toro, Ko je ipin mi Oluwa: K'ebun yi je temi. Emi i ba le joko lai, Bi Maria, lese Jesu; Keyi je ayo mi; Ko janiyan atife mi, Ko si j'orun fun mi laye Lati ma gbohun Re. Source: YBH #266