Posts

Onigbagbo E Bu Sayo

Author: John E. Bowers Onigbagbo e bu sayo! Ojo nla loni fun wa Korun fayo korin kikan, Kigbo atodan gberin E ho! E yo! Okun atodo gbogbo. E jumo yo, gbogbo eda, Laye yi ati lorun, Ki gbogbo ohun alaaye Nile, loke, yin Jesu E fogo fun Oba nla ta bi loni. Gbohun yin ga, "Om'Afrika" Eyin iran Yoruba; Ke "Hosanna" lohun gooro Jake jado ile wa. Koba gbogbo, Juba Jesu Oba wa. E damuso! E damuso! E ho ye! Ke si ma yo, Itegun Esu fo wayi, "Iru-omobinrin" de. Halleluyah! Olurapada, Oba. E gbohun yin ga, Serafu, Kerubu, leba ite; Angeli ateniyan mimo, Pelu gbogbo ogun orun. E ba wa yo! Odun idasile de. Metalokan, Eni Mimo Baba Olodumare Emi Mimo, Olutunnu, Jesu, Olurapada, Gba iyin wa 'Wo nikan logo ye fun. Christians lift your voice in praises On this memorable day Sing in gladness, let your voices Sing all over vale and dale Laud Hosannas, laud Hosannas, Sea and streams all join the strain. Come ye peo...

WA EYIN OLOOTO

Words: John Francis Wade Wa eyin olooto Layo ati'segun Wa kalo, wa kalo si Betlehem Wa ka lo wo o! Oba awon Angeli! E wa ka lo juba Re/2X E wa ka lo juba Kristi Oluwa Olodumare ni, Imole Ododo, Ko si korira inu wundia; Olorun paapaa ni Ti a bi, ti a ko da; Angeli, e korin, Korin itoye Re, Ki gbogbo eda orun si gberin: Ogo f'Olorun Li oke orun, Nitooto, a wole F'Oba ta bi loni; Jesu, Iwo lawa n fi ogo fun, 'Wo Omo Baba, T'O mara wa wo! O come, all ye faithful, joyful and triumphant! O come ye, O come ye to Bethlehem! Come and behold him, born the King of angels; O come, let us adore him, O come, let us adore him, O come, let us adore him, Christ the Lord! God of God, Light of Light eternal, lo, he abhors not the virgin’s womb; Son of the Father, begotten, not created; Sing, choirs of angels, sing in exultation, sing, all ye citizens of heaven above: “Glory to God, all glory in the highest!” Yea, Lord, we greet thee, bor...

GBO OHUN ALORE

Words: Horatius Bonar Gbo ohun alore, Ji, ara, ji; Jesu ma fere de, Ji, ara, ji, Omo oru ni sun, Omo imole leyin, Ti yin logo didan, Ji, ara, ji. So fegbe to ti ji, Ara, sora; Ase Jesu daju, Ara, sora; E se b'olusona Nilekun Oluwa yin Bi O tile pe de, Ara, sora. Gbo ohun iriju, Ara, sise; Ise na kari wa, Ara, sise; Ogba Oluwa wa, Kun fun'se nigba gbogbo Yoo si fun wa lere, Ara sise. Gbo ohun Oluwa wa, E gbadura; Be fe kinu Re dun E gbadura; Ese 'mu beru wa, Alailera si ni wa; Ni ijakadi yin, E gbadura Ko orin ikehin, Yin, ara, yin; Mimo ni Oluwa. Yin, ara, yin: Ki lo tun ye ahon, To fere b'Angel' korin, T'y'o ro lorun titi, Yin, ara, yin. Hark! ’tis the watchman’s cry, Wake, brethren, wake! Jesus our Lord is nigh; Wake, brethren, wake! Sleep is for sons of night; Ye are children of the light, Yours is the glory bright; Wake, brethren, wake! Call to each waking band, Watch, brethren, watch! Clear is...

Aajin Jin, Oru Mimo

Words: Joseph Mohr Aajin jin, oru mimo, Ookun su, mole de, Awon Olus'aguntan n sona, Omo to wa loju orun,   Sinmi n'nu alafia   Sinmi n'nu alafia. Aajin jin, oru mimo, Mole de, ookun sa, Oluso aguntan gborin Angel', Kabiyesi aleluya Oba.   Jesu Olugbala de   Jesu Olugbala de. Aajin jin, oru mimo, 'Rawo orun tan mole Wo awon Amoye ila orun Mu ore won wa fun Oba wa,   Jesu Olugbala de   Jesu Olugbala de. Aajin jin, oru mimo, 'Rawo orun tan 'mole Ka pelu awon Angel korin, Kabiyesi aleluya Oba   Jesu Olugbala de   Jesu Olugbala de. Silent night! Holy night! All is calm, all is bright ’round yon virgin mother and child! Holy infant, so tender and mild, sleep in heavenly peace, sleep in heavenly peace. Silent night! Holy night! Shepherds quake at the sight. Glories stream from heaven afar, heavenly hosts sing: “Alleluia! Christ the Savior is born! Christ the Savior is born!” Silent night! Holy night! Son o...

O De

O de, Kristi Oluwa, Lat'ibugbe Re lorun, Lat'ite alafia, O wa si aginju wa. Alade Alana De lati ru 'ponju wa; O de, lati f'imole, Le okun oru wa lo. Jesus Christ the Lord has come, From His Father's throne above. From above the throne of peace. He came to this wilderness. Christ the Lord the Prince of Peace Come to bear all our burden, He has come to give us light, Drives away all our nightmare. Source: Hymnaro #92 Aroyehun ©2013

Wo Oju Sanma

Wo oju sanma ohun ni, Wo lila orun ooro; Ji loju orun, okan mi, Dide ko si ma sora; Olugbala Tun n pada bo wa saye. Ope ti mo ti n reti Re, L'are lokan mi n duro, Aye ko ni ayo fun mi, Nibi ti ko tan 'mole, Olugbala, 'Gbawo n'Iwo o pada? Igbala mi sunm' etile, Oru fere koja na, Je ki n wa nipo irele, Ki n s'afojusona Re, Olugbala Titi n o fi roju Re. Je ki fitila mi ma jo, Ki n ma sako kiri mo, Ki n sa ma reti abo Re, Lati mu mi lo sile; Olugbala Yara k'O ma bo kankan. Behold, see yonder horizon Behold the morning sunrise Wake from thy deep sleep, thou my heart Arise and be thou watchful; Blessed Saviour, blessed Saviour Coming again to the earth It's long I've been expecting Thee My weary heart long doth wait The world has no more joy for me, E'er its light has become dark Blessed Saviour, blessed Saviour, When will Thou come back again My salvation doth draw nearer The dark night is almost gone Let...

Ma Wole, Jesu Ta N Reti

Ma wole, Jesu ta n reti, Ta bi lati gba ni la! Gba wa low'ese ate'eru; Ka ri'sinmi ninu Re. Ipa ati'tunu Israel', Ireti awon mimo; Olufe gbogbo orile, Ayo okan ti n reti. A bi O lati gbeda la, Eniyan--sugbon Olorun-- Lati joba lai ninu wa, Mu 'joba rere re wa. Nipa Emi Re to wa lai, Nikan joba ninu wa; Nipa 'toye Re to po to Gbe wa site ogo Re. Long expected, our Lord Jesus, Born to give us salvation, Redeem us from fear and sin Give us peace eternally/2x Pow’r, peace and joy for Israel, The hope of righteous men, Lover of the entire nations; Joy for the expectant souls/2x Born to give us salvation, God born of human flesh To reign in heart for ever, Send down Thou good governance/2x By the Spirit forever more, Reign forever in our souls By the great mercies forever, Reign with You all ever more /2x Source: Hymnaro #88 Aroyehun ©2013