Posts

OJO NLA

Words: Philip Doddridge, refrain from Wesleyan Sacred Harp Ojo ayo l’ ojo ti mo Yan O, 'Wo Olugbala mi; O to ki okan mi ko yo, K’o si sayo re kakiri. Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki n ma gbadura Ki nma sora ki nsi ma yo Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu. A ti pari ise nla naa Emi t'Oluwa O'n temi O fa mi mo si tele O Mo yo lati gba ipe naa. Simi aisokan, okan mi, Simi lori ipinnu yi; Mo ripa to lola nibi, Ayo orun kun mi laya. Orun giga to gbeje mi, Yoo gbo lotun lojojumo, Titi n o fi fibukun fun, Idapo yi loju iku. O happy day, that fixed my choice On Thee, my Savior and my God! Well may this glowing heart rejoice, And tell its raptures all abroad. Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! He taught me how to watch and pray, And live rejoicing every day: Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! O happy bond, that seals my vows To Him Who merits all my love! Let cheerful an...

A Fope F'Olorun

Words:Martin Rinkart, circa 1636 (Nun danket alle Gott); first appeared in Praxis Pietatis Melica, by Johann Crüger (Berlin, Germany: 1647); translated from German to English by Catherine Winkworth, 1856 . A fope f'Olorun lokan ati lohun wa: Eni sohun 'yanu, n'nu Eni taraye n yo. Gba ta wa lomo'wo, Oun na lo n toju wa, O si febun ife se'toju wa sibe. Oba Onibuore, ma fi wa sile lailai, Ayo ti ko lopin oun 'bukun yoo je tiwa. Pa wa mo ninu ore, to wa 'gba ba damu, Yo wa ninu ibi laye ati lorun. Ka fiyin oun ope f'Olorun Baba, Omo Ati Emi Mimo ti O ga julo lorun Olorun kan lailai taye atorun n bo Bee l'O wa d'isinyi,  beeni y'O wa lailai. Now thank we all our God, with heart and hands and voices, Who wondrous things has done, in whom this world rejoices; Who from our mothers’ arms has blessed us on our way With countless gifts of love, and still is ours today. O may this bounteous God through all our life be near us, ...

Onigbagbo E Bu Sayo

Author: John E. Bowers Onigbagbo e bu sayo! Ojo nla loni fun wa Korun fayo korin kikan, Kigbo atodan gberin E ho! E yo! Okun atodo gbogbo. E jumo yo, gbogbo eda, Laye yi ati lorun, Ki gbogbo ohun alaaye Nile, loke, yin Jesu E fogo fun Oba nla ta bi loni. Gbohun yin ga, "Om'Afrika" Eyin iran Yoruba; Ke "Hosanna" lohun gooro Jake jado ile wa. Koba gbogbo, Juba Jesu Oba wa. E damuso! E damuso! E ho ye! Ke si ma yo, Itegun Esu fo wayi, "Iru-omobinrin" de. Halleluyah! Olurapada, Oba. E gbohun yin ga, Serafu, Kerubu, leba ite; Angeli ateniyan mimo, Pelu gbogbo ogun orun. E ba wa yo! Odun idasile de. Metalokan, Eni Mimo Baba Olodumare Emi Mimo, Olutunnu, Jesu, Olurapada, Gba iyin wa 'Wo nikan logo ye fun. Christians lift your voice in praises On this memorable day Sing in gladness, let your voices Sing all over vale and dale Laud Hosannas, laud Hosannas, Sea and streams all join the strain. Come ye peo...

WA EYIN OLOOTO

Words: John Francis Wade Wa eyin olooto Layo ati'segun Wa kalo, wa kalo si Betlehem Wa ka lo wo o! Oba awon Angeli! E wa ka lo juba Re/2X E wa ka lo juba Kristi Oluwa Olodumare ni, Imole Ododo, Ko si korira inu wundia; Olorun paapaa ni Ti a bi, ti a ko da; Angeli, e korin, Korin itoye Re, Ki gbogbo eda orun si gberin: Ogo f'Olorun Li oke orun, Nitooto, a wole F'Oba ta bi loni; Jesu, Iwo lawa n fi ogo fun, 'Wo Omo Baba, T'O mara wa wo! O come, all ye faithful, joyful and triumphant! O come ye, O come ye to Bethlehem! Come and behold him, born the King of angels; O come, let us adore him, O come, let us adore him, O come, let us adore him, Christ the Lord! God of God, Light of Light eternal, lo, he abhors not the virgin’s womb; Son of the Father, begotten, not created; Sing, choirs of angels, sing in exultation, sing, all ye citizens of heaven above: “Glory to God, all glory in the highest!” Yea, Lord, we greet thee, bor...

GBO OHUN ALORE

Words: Horatius Bonar Gbo ohun alore, Ji, ara, ji; Jesu ma fere de, Ji, ara, ji, Omo oru ni sun, Omo imole leyin, Ti yin logo didan, Ji, ara, ji. So fegbe to ti ji, Ara, sora; Ase Jesu daju, Ara, sora; E se b'olusona Nilekun Oluwa yin Bi O tile pe de, Ara, sora. Gbo ohun iriju, Ara, sise; Ise na kari wa, Ara, sise; Ogba Oluwa wa, Kun fun'se nigba gbogbo Yoo si fun wa lere, Ara sise. Gbo ohun Oluwa wa, E gbadura; Be fe kinu Re dun E gbadura; Ese 'mu beru wa, Alailera si ni wa; Ni ijakadi yin, E gbadura Ko orin ikehin, Yin, ara, yin; Mimo ni Oluwa. Yin, ara, yin: Ki lo tun ye ahon, To fere b'Angel' korin, T'y'o ro lorun titi, Yin, ara, yin. Hark! ’tis the watchman’s cry, Wake, brethren, wake! Jesus our Lord is nigh; Wake, brethren, wake! Sleep is for sons of night; Ye are children of the light, Yours is the glory bright; Wake, brethren, wake! Call to each waking band, Watch, brethren, watch! Clear is...

Aajin Jin, Oru Mimo

Words: Joseph Mohr Aajin jin, oru mimo, Ookun su, mole de, Awon Olus'aguntan n sona, Omo to wa loju orun,   Sinmi n'nu alafia   Sinmi n'nu alafia. Aajin jin, oru mimo, Mole de, ookun sa, Oluso aguntan gborin Angel', Kabiyesi aleluya Oba.   Jesu Olugbala de   Jesu Olugbala de. Aajin jin, oru mimo, 'Rawo orun tan mole Wo awon Amoye ila orun Mu ore won wa fun Oba wa,   Jesu Olugbala de   Jesu Olugbala de. Aajin jin, oru mimo, 'Rawo orun tan 'mole Ka pelu awon Angel korin, Kabiyesi aleluya Oba   Jesu Olugbala de   Jesu Olugbala de. Silent night! Holy night! All is calm, all is bright ’round yon virgin mother and child! Holy infant, so tender and mild, sleep in heavenly peace, sleep in heavenly peace. Silent night! Holy night! Shepherds quake at the sight. Glories stream from heaven afar, heavenly hosts sing: “Alleluia! Christ the Savior is born! Christ the Savior is born!” Silent night! Holy night! Son o...

O De

O de, Kristi Oluwa, Lat'ibugbe Re lorun, Lat'ite alafia, O wa si aginju wa. Alade Alana De lati ru 'ponju wa; O de, lati f'imole, Le okun oru wa lo. Jesus Christ the Lord has come, From His Father's throne above. From above the throne of peace. He came to this wilderness. Christ the Lord the Prince of Peace Come to bear all our burden, He has come to give us light, Drives away all our nightmare. Source: Hymnaro #92 Aroyehun ©2013