Posts

Ki N Mo Nipa Jesu Sii / More About Jesus

Author: E. E. Hewitt (1887 ) Mo fe mo nipa Jesu sii, F'or' ofe Re h' elomiran; Ki n le ri 'gbala kikun Re, Ki n mo 'fe 'ni to ku fun mi. Egbe: Ki n mo nipa Jesu sii, Ki n mo nipa Jesu sii; Ki n le ri 'gbala kikun Re, Ki n mo 'fe 'ni to ku fun mi N o ko nipa Jesu sii, Ki n da 'fe Re mimo mo si i; K' Em' Olorun j'oluko mi, Fi ona ti Kristi han mi. Ki n mo Jesu si n'oro Re, Ki n ma b'Oluwa mi soro; Ki n si gbo 'ro Re lokokan, So 'ro 'tito Re di t'emi. Ki n mo Jesu l 'ori 'te Re, Pel' oro gbogbo Ogo Re; Mo bi'joba Re ti n po si, Bibo Re Oba 'lafia Source: YBH #618 More about Jesus  would I know, More of His grace to others show; More of His saving fulness see, More of His love who died for me. Refrain: More, more about Jesus, More, more about Jesus; More of His saving fulness see, More of His love who died for me. More about Jesus let me lea

Yíyẹ L'Ọdaguntan / Worthy Is The Lamb

Image
Author: Darlene Zschech Translated by Ayobami Temitope Kehinde on April 12, 2020 O ṣeun f'ágbèlébù Olúwa  O ṣeun fún ’díyelé t'O san O gbẹ́ṣẹ̀, ’tìjú mi rù Nifẹ̀ l'O wa Pẹl' or'ọfẹ ìyanu O ṣeun fun ’fẹ́ yii, Olúwa  O ṣeun f' ọwọ́ ta gun niṣo  O wẹ mi n'nú iṣan Rẹ,  Wàyíí mo mọ̀  ’Dariji, ’tẹwogba Rẹ.  Egbe: Yíyẹ l'Ọdaguntan T'O joko lor' itẹ́  A de Ọ lade ọpọlọpọ O ń jọba n'iṣẹgun Gbigbega ni Ọ Jésù, Ọm' Ọlọrun Ààyò ọ̀run ti a kan mọ́gi  Yíyẹ l'Ọdaguntan Yíyẹ l'Ọdaguntan Thank you for the cross, Lord Thank you for the price You paid Bearing all my sin and shame In love You came And gave amazing grace Thank you for this love, Lord Thank you for the nail pierced hands Washed me in Your cleansing flow Now all I know Your forgiveness and embrace Refrain: Worthy is the Lamb Seated on the throne Crown You now with many crowns You reign victorious

'Bukun Ni Fun Ohun / Blest Be The Tie That Binds

Author: John Fawcett, pub. 1782 'Bukun ni fun ohun, T' o de wa po n'nu 'fe; Idapo awon olufe, Dabi ijo t' orun. Niwaju 'te Baba, Li awa ngbadura; Okan n' ireti at' eru, Ati ni itunu. Awa mb' ara wa pin Ninu wahala wa; Awa si mb' ara wa sokun Ninu 'banuje wa. Nigbat' a ba pinya, Inu wa a baje; Sibe okan wa y'o j' okan N' ireti ipade. Source: YBH #318 Blest be the tie that binds Our hearts in Christian love; The fellowship of kindred minds Is like to that above. Before our Father’s throne, We pour our ardent prayers; Our fears, our hopes, our aims are one— Our comforts and our cares. We share our mutual woes; Our mutual burdens bear; And often for each other flows The sympathizing tear. When we asunder part, It gives us inward pain; But we shall still be joined in heart, And hope to meet again. From sorrow, toil, and pain, And sin we shall be free; And perfect lo

Alafia, Ni Aye Ese Yi / Peace, Perfect Peace

Image
Author: Edward H. Bickersteth, Jr., 1875 Alafia, ni aye ese yi Eje Jesu n wipe, "Alafia!" Alafia, ninu opo lala? Lati se ife Jesu ni 'simi. Alafia, n'nu igbi 'banuje? L' aiya Jesu n' idakeroro wa. Alafia, n'nu ijiya lile? Ikaanu Jesu mu 'bale okan wa. Alafia, gb' ara wa wa l' ajo? N' ipamo Jesu, iberu ko si. Alafia, b' a ko tile m' ola? Sugbon a mo pe Jesu wa lailai. Alafia, nigb' akoko iku? Olugbala wa ti segun iku. O to: 'jakadi aye fere pin, Jesu y' o pe wa s' orun alafia. Source: Stanzas 1-3 & 5-8 from YBH #259 Stanza 4 translated by Ayobami Temitope Kehinde (07/04/2020) Peace, perfect peace, in this dark world of sin? The blood of Jesus whispers peace within. Peace, perfect peace, by thronging duties pressed? To do the will of Jesus, this is rest. Peace, perfect peace, with sorrows surging round? On Jesus’ bosom naught but calm is found. Peace, perfect peace,

A O Ha Pade Leti Odo

Author: Robert Lowry A o ha pade l' eti odo, T' ese angeli ti te, 'T o mo gara bi kristali, Leba ite Olorun? A o pade l' eti odo, Odo didan, odo didan na, Pel' awon mimo leb' odo, T' o nsan leba ite na? L' eti bebe odo na yi, Pel' Olus'-agutan wa, A o ma rin, a o sin, B' a ti ntele 'pase Re. K' a to de odo didan na, A o s' eru wa kale; Jesu yio gba eru ese Awon ti yio de l' ade. Nje leba odo tutu na, Ao r' oju Olugbala; Emi wa ki o pinya mo, Yio korin ogo Re. Source: YBH #487 Shall we gather at the river, Where bright angel feet have trod; With its crystal tide forever Flowing by the throne of God? Refrain: Yes, we'll gather at the river, The beautiful, the beautiful river; Gather with the saints at the river That flows by the throne of God. On the margin of the river, Washing up its silver spray, We will walk and worship ever, All the happy golden day. Ere we reach the shi

Ore wo la ni bi Jesu

William Cowper, 1731-1800 Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa! Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si! Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po, Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re. Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi? A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa. Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro, Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa. Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa? Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa. Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa. Yo gbe o soke lapa re, Iwo yo si ri itunu. What a friend we have in Jesus All our sins and grief to bear What privilege to carry everything to God in prayer  What a peace we often forfeit  What a needless pain we bear All because we do not carry everything to God in prayer.  Have we trials and tempations? Is there trouble anywhere? We should never be discouraged  Take it to the Lord in prayer.  Can we find a friend so faithful ? Who will all our sorrows sh

Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú! / How Marvellous! How Wonderful!

Image
Author: Charles Hutchinson Gabriel Yoruba Translator: Ayobami Temitope Kehinde Ní ìyanu ni mo dúró Níwájú Jésù Nasaret' Mo sì ń wòye b' Ó ti fẹ́ mi tó Ẹlẹ́ṣẹ̀ ta dá lẹbi Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú! Ni orin mi yó ma jẹ̀ Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú! Ìfẹ́ Olùgbàlà mi.  Fún mi, nín' ọgbà ló gbàdúrà "Jẹ́ kí ìfẹ́ Rẹ kó ṣẹ." Ko sun tori irora Rẹ Ṣùgbọ́n O sunro ẹjẹ fun mi.  Tẹduntẹdun l'angẹli woo, Wọn wa la'taye 'mọlẹ Lati gbé E ró 'nu ' banuje To ru fokan mi lalẹ yẹn Ó mẹ́ṣẹ̀ àti 'bànújẹ́ mi, Ò fi wọ́n ṣe Tirẹ̀ Ó gbẹ́rù wúwo dé Kalfari Ó da jìyà, Ó dá kú. 'Gbà pẹ̀lú àwọn táa rà padà  Mo rójú Rẹ̀ níkẹhìn  N ò fayọ̀ kọrin títí ayé Orin ìfẹ́ Rẹ̀ fún mi.  I stand amazed in the presence Of Jesus the Nazarene, And wonder how He could love me, A sinner condemned, unclean Refrain How marvellous! How wonderful! And my song shall ever be: How marvelous!