Aye Si N Be Nile Od'aguntan
Words: Horatius Bonar (1808-1889), 1872 Music: Cantus (Uzziah C. Burnap, 1895) Aye si n be nile Od'agutan Ewa ogo Re n pe O pe ma bo Wole, wole, wole nisisiyi Ojo lo tan, orun si fere wo, Okunkun de tan, mole n koja lo Wole, wole, wole nisisiyi Ile iyawo na kun fun ase! Wole, wole to Oko 'yawo: Wole, wole, wole nisisiyi. "Aye si n be!" ilekun si sile, Ilekun ife: iwo ko pe ju, Wole, wole, wole nisisiyi Wa gbebun 'fe ayeraye lofe! Wole, wole, wole nisisiyi. Kiki ayo lo wa nibe, wole! Awon Angel lo npe o fun ade; Wole, wole, wole nisisiyi. Lohun rara nipe ife naa ndun! Wa, ma jafara, wole ase naa. Wole, wole, wole nisisiyi. O n kun, o n kun! Ile ayo na n kun! Yara! mase pe, ko kun ju fun o. Wole, wole, wole nisisiyi. Kile to su, ilekun na le ti! 'Gbana, o kabamo! "O se! O se!" O se! O se! Ko saye mo, o se! "Yet there is room": the Lamb's bright hall of song, With its fair glory, beckons thee along;...