Gbo 'gbe ayo! Oluwa de / Hark! The Glad Sound
Author:Philip Doddridge Gbo 'gbe ayo! Oluwa de, Jesu t' a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K' ohun mura ko ' rin O de lati t' onde sile, L' oko eru Esu; 'Lekun 'de fo niwaju Re, Sekeseke 'rin da. O delarin 'baje aiye Lati tan 'mole Re, Lati fun awon afoju N' iriran f' oju won. O de! 'Tunu f' okan 'rora, Iwosan f' agbogbe; O de pel' opo 'sura Re Fun awon talaka. Hosanna wa, Oba 'lafia Ao kede bibo Re; Gbogbo orun y'o ma korin Oruko t' a feran. Source: YBH #90 Hark, the glad sound! The Savior comes, the Savior promised long! Let ev'ry heart prepare a throne, and ev'ry voice a song. He comes the pris'ners to release, in Satan’s bondage held; the gates of brass before Him burst, the iron fetters yield. He comes from thickest films of vice To clear the mental ray And on the eyeballs of the blind To pour celestial day. ...