Ore wo la ni bi Jesu
William Cowper, 1731-1800 Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa! Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si! Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po, Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re. Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi? A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa. Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro, Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa. Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa? Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa. Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa. Yo gbe o soke lapa re, Iwo yo si ri itunu. What a friend we have in Jesus All our sins and grief to bear What privilege to carry everything to God in prayer What a peace we often forfeit What a needless pain we bear All because we do not carry everything to God in prayer. Have we trials and tempations? Is there trouble anywhere? We should never be discouraged Take it to the Lord in prayer. Can we find a friend so faithful ? Who will all our sorrows sh