Posts

A O Ha Pade Leti Odo

Author: Robert Lowry A o ha pade l' eti odo, T' ese angeli ti te, 'T o mo gara bi kristali, Leba ite Olorun? A o pade l' eti odo, Odo didan, odo didan na, Pel' awon mimo leb' odo, T' o nsan leba ite na? L' eti bebe odo na yi, Pel' Olus'-agutan wa, A o ma rin, a o sin, B' a ti ntele 'pase Re. K' a to de odo didan na, A o s' eru wa kale; Jesu yio gba eru ese Awon ti yio de l' ade. Nje leba odo tutu na, Ao r' oju Olugbala; Emi wa ki o pinya mo, Yio korin ogo Re. Source: YBH #487 Shall we gather at the river, Where bright angel feet have trod; With its crystal tide forever Flowing by the throne of God? Refrain: Yes, we'll gather at the river, The beautiful, the beautiful river; Gather with the saints at the river That flows by the throne of God. On the margin of the river, Washing up its silver spray, We will walk and worship ever, All the happy golden day. Ere we reach the shi

Ore wo la ni bi Jesu

William Cowper, 1731-1800 Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa! Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si! Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po, Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re. Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi? A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa. Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro, Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa. Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa? Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa. Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa. Yo gbe o soke lapa re, Iwo yo si ri itunu. What a friend we have in Jesus All our sins and grief to bear What privilege to carry everything to God in prayer  What a peace we often forfeit  What a needless pain we bear All because we do not carry everything to God in prayer.  Have we trials and tempations? Is there trouble anywhere? We should never be discouraged  Take it to the Lord in prayer.  Can we find a friend so faithful ? Who will all our sorrows sh

Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú! / How Marvellous! How Wonderful!

Image
Author: Charles Hutchinson Gabriel Yoruba Translator: Ayobami Temitope Kehinde Ní ìyanu ni mo dúró Níwájú Jésù Nasaret' Mo sì ń wòye b' Ó ti fẹ́ mi tó Ẹlẹ́ṣẹ̀ ta dá lẹbi Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú! Ni orin mi yó ma jẹ̀ Ìyanilẹ́nu! Ìjọnilójú! Ìfẹ́ Olùgbàlà mi.  Fún mi, nín' ọgbà ló gbàdúrà "Jẹ́ kí ìfẹ́ Rẹ kó ṣẹ." Ko sun tori irora Rẹ Ṣùgbọ́n O sunro ẹjẹ fun mi.  Tẹduntẹdun l'angẹli woo, Wọn wa la'taye 'mọlẹ Lati gbé E ró 'nu ' banuje To ru fokan mi lalẹ yẹn Ó mẹ́ṣẹ̀ àti 'bànújẹ́ mi, Ò fi wọ́n ṣe Tirẹ̀ Ó gbẹ́rù wúwo dé Kalfari Ó da jìyà, Ó dá kú. 'Gbà pẹ̀lú àwọn táa rà padà  Mo rójú Rẹ̀ níkẹhìn  N ò fayọ̀ kọrin títí ayé Orin ìfẹ́ Rẹ̀ fún mi.  I stand amazed in the presence Of Jesus the Nazarene, And wonder how He could love me, A sinner condemned, unclean Refrain How marvellous! How wonderful! And my song shall ever be: How marvelous!

K'ore Ofe Krist' Oluwa

Image
Author: John Newton K'ore ofe Krist' Oluwa, Ife Baba ail'opin, Oju rere Emi mimo, K'o t'oke ba s'ori wa; Bayi l'a le wa n'irepo. Pel' ara wa 't' Oluwa; K'a si le ni 'dapo didun, Ayo t'aye ko le ni. May the grace of Christ our Savior and the Father's boundless love, with the Holy Spirit's favor, rest upon us from above. Thus may we abide in union with each other and the Lord, and possess, in sweet communion, joys which earth cannot afford. Amen.

Ojo Oni Lo Tan

Author: S. Baring Gould Ojo oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su. Okunkun bo ile, Awon 'rawo yo; Eranko at' eiye, Lo si 'busun won. Jesu f' orun didun, F' eni alare; Je ki ibukun Re, Pa oju mi de. Je k' omo kerekere, La ara rere; S' oloko t' ewu nwu Ni oju omi. Ma to ju alaisan, Ti ko r' orun sun; Da olosa lekun L'ona ibi won. Ninu gbogbo oru, Je k' angeli Re, Ma se oluso mi, Lori eni mi. Source: YBH #62 Gbat' ile ba si mo, Je k' emi dide, B' omo ti ko l' ese, Ni iwaju Re. Ogo ni fun Baba, Ati fun Omo, Ati f' Emi Mimo, Lai ati lailai. Now the day is over, Night is drawing nigh, Shadows of the evening Steal across the sky. Now the darkness gathers, Stars begin to peep, Birds, and beasts and flowers Soon will be asleep. Jesus, give the weary Calm and sweet repose; With Thy tend'rest blessing May o

Gbo 'gbe ayo! Oluwa de / Hark! The Glad Sound

Author:Philip Doddridge Gbo 'gbe ayo! Oluwa de, Jesu t' a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K' ohun mura ko ' rin O de lati t' onde sile, L' oko eru Esu; 'Lekun 'de fo niwaju Re, Sekeseke 'rin da.     O delarin 'baje aiye Lati tan 'mole Re, Lati fun awon afoju N' iriran f' oju  won. O de! 'Tunu f' okan 'rora, Iwosan f' agbogbe; O de pel' opo 'sura Re Fun awon talaka. Hosanna wa, Oba 'lafia Ao kede bibo Re; Gbogbo orun y'o ma korin Oruko t' a feran. Source: YBH #90 Hark, the glad sound! The Savior comes, the Savior promised long! Let ev'ry heart prepare a throne, and ev'ry voice a song. He comes the pris'ners to release, in Satan’s bondage held; the gates of brass before Him burst, the iron fetters yield. He comes from thickest films of vice To clear the mental ray And on the eyeballs of the blind To pour celestial day.

Okan Mi Sunmo 'Te Anu / Approach, My Throne, The Mercy Seat

Author:John Newton Okan mi, sunmo 'te anu, Nibi Jesu ngb' ebe, F' irele wole l' ese Re, 'Wo ko le gbe nibe. Ileri Re ni ebe mi, Eyi ni mo mu wa; Iwo npe okan t' eru npa, Bi emi, Oluwa. Eru ese wo mi l' orun, Esu nse mi n' ise; Ogun l' ode, eru ninu, Mo wa isimi mi. Se Apata at' Asa mi, Ki nfi O se abo; Ki ndoju ti Olufisun, Ki nso pe Kristi ku. Ife iyanu! Iwo ku, Iwo ru itiju; Ki elese b' iru emi, Le be l' oruko Re. Source: YBH #212 Approach, my soul, the mercy seat where Jesus answers prayer; there humbly fall before his feet, for none can perish there. Thy promise is my only plea; with this I venture nigh: thou callest burdened souls to thee, and such, O Lord, am I. Bowed down beneath a load of sin, by Satan sorely pressed, by war without and fears within, I come to thee for rest. Be thou my shield and hiding place, that, sheltered near thy side, I